Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

JUNE 21, 2024
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí Ti Ọdún 2024 #4

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí Ti Ọdún 2024 #4

Nínú ìròyìn yìí, a máa rí báwọn ará wa lọ́kùnrin àti lóbìnrin tí wọ́n fi sẹ́wọ̀n nítorí ohun tí wọ́n gbà gbọ́ ṣe ń “fi ire ṣẹ́gun ibi.”​—Róòmù 12:21.