Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2002

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2002

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2002

Ó ń tọ́ka sí ìtẹ̀jáde tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

Akitiyan Tó Ń Gbé Ìlànà Ìwà Rere Ga (Mòsáńbíìkì), 11/15

Àpéjọ Àgbáyé Yóò Wáyé Lọ́dún 2003, 7/1

Àpéjọ “Àwọn Olùkọ́ni ní Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run,” 1/15

A Ṣí Àwọn Gbọ̀ngàn Ìjọba Sílẹ̀ fún Gbogbo Èèyàn Láti Wò, 11/1

Àwọn Ajẹ́rìíkú Òde Òní (Sweden), 2/1

Àwọn Alátìlẹyìn Ìjọsìn Tòótọ́ (ọrẹ), 11/1

Àwọn Èwe Tó Ń Tuni Lára, 9/15

Àwọn Ìpàdé, 3/15

Àwọn Òkè Ńlá Philippines, 4/15

Àwọn Orílẹ̀-Èdè Balkan (Ìtumọ̀ Ayé Tuntun), 10/15

Àwọn Ọ̀dọ́ Tó Fẹ́ràn Òtítọ́, 10/1

Àwọn Pásítọ̀ Tó Mọyì Àwọn Ìwé Tí Russell Kọ, 4/15

Ayẹyẹ Ìkẹ́kọ̀ọ́yege ní Gílíádì, 6/15, 12/15

Bí Ọmọ Kan Ṣe Ran Bàbá Rẹ̀ Lọ́wọ́, 5/1

Gbọ̀ngàn Ìjọba Kan Gba Àmì Ẹ̀yẹ (Finland), 10/1

Ìbísí Bíbùáyà Mú Kí Ìmúgbòòrò Pọn Dandan (Àwọn Gbọ̀ngàn Ìjọba), 5/15

“Ìdí Tí Mo Fi Dá Owó Yín Padà,” 8/15

‘Ìfẹ́ Wa Ti Jinlẹ̀ Sí I’ (òkè ayọnáyèéfín ní Japan), 3/1

Ìpàdé Ọdọọdún ti 2001, 4/1

Iṣẹ́ Àtàtà Ń Yin Ọlọ́run Lógo (Ítálì), 1/15

Kí Ló Gbà Láti Ní Ẹ̀rí Ọkàn Mímọ́? 2/15

Lórí Tábìlì Ọ̀gákọ̀ (R. G. Smith), 12/1

“Máa Ṣe Ohun Rere sí Gbogbo Ènìyàn,” 7/15

Ọmọdé Gbọ́n, Àgbà Gbọ́n (àwọn ọmọdé tó ń dáwó), 2/1

Wọ́n Ti Mọ̀wé Kà (Solomon Islands), 8/15

ÀWỌN OLÙPÒKÌKÍ ÌJỌBA RÒYÌN

2/1, 4/1, 6/1, 8/1, 10/1, 11/1

BÍBÉLÌ

Akitiyan Láti Tẹ Bíbélì Lédè Gíríìkì Òde Òní, 11/15

Ìtumọ̀ Septuagint, 9/15

Ọba Henry Kẹjọ àti Bíbélì, 1/1

ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ

Àánú Jèhófà ń pẹ̀rọ̀ sí ìdájọ́ òdodo rẹ̀ kẹ̀? 3/1

Àgbàlá níbi tí “ogunlọ́gọ̀ ńlá” ti ń sìn (Ìṣí 7:15), 5/1

Àwọn ìgbà wo ló yẹ kí Kristẹni obìnrin borí rẹ̀? 7/15

Gbígbàdúrà láìsọ pé “ní orúkọ Jésù,” 4/15

Ìgbéyàwó láàárín àwọn ìbátan, 2/1

Ìtumọ̀ “dúró títí dé orí ẹ̀jẹ̀” (Héb 12:4), 2/15

Iye àwọn ọmọ Jésè (1 Sa 16:10, 11; 1 Kr 2:13-15), 9/15

Lúsíférì (Isa 14:12, KJ), 9/15

Ǹjẹ́ àìpé Màríà ran Jésù? 3/15

Ǹjẹ́ Ébẹ́lì mọ̀ pé ó pọ̀n dandan láti fi ẹran rúbọ? 8/1

Ǹjẹ́ ó bójú mu láti lọ sọ ọ̀rọ̀ ìsìnkú ẹni tó pa ara rẹ̀? 6/15

Ǹjẹ́ ó bọ́gbọ́n mu láti lọ bá wọn ṣètò ìsìnkú tàbí ìgbéyàwó nínú ṣọ́ọ̀ṣì? 5/15

Ǹjẹ́ ó lòdì láti kọ́ iyàn tí owó rẹ̀ kò jù táṣẹ́rẹ́? 11/1

Ọmọ títọ́ nínú ilé tí ìsìn ti yàtọ̀ síra, 8/15

Ṣé dandan ni ká ri aláàbọ̀ ara tàbí ẹni tí ipò rẹ̀ gbẹgẹ́ gan-an bọmi pátápátá? 6/1

Ṣé gbogbo ìgbà la gbọ́dọ̀ san ẹ̀jẹ́ tá a bá jẹ́ fún Ọlọ́run? 11/15

Ṣe ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ la máa tàn jẹ nígbà ìdánwò ìkẹyìn? (Ìṣí 20:8), 12/1

Ríra ilẹ̀ Gbọ̀ngàn Ìjọba lọ́wọ́ àwọn ẹlẹ́sìn mìíràn kẹ̀? 10/15

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

Agbára Láti Ronú, 8/15

‘Ẹ Máa Dárí Ji Ara Yín Fàlàlà,’ 9/1

“Ẹ Máa Ṣe Olùṣọ́ Àgùntàn Agbo Ọlọ́run,” 11/15

Ẹ̀mí Ìfọ̀rọ̀rora-Ẹni-Wò, 4/15

Ẹ̀yin Alàgbà—Ẹ Kọ́ Àwọn Ẹlòmíràn, 1/1

Fífi Ìfẹ́ Hàn Nínú Agbo Ìdílé, 12/15

Fún Ọwọ́ Rẹ Lókun, 12/1

Gbin Òdodo, Kí O sì Ká Inú-Rere-Onífẹ̀ẹ́ (Òwe 11), 7/15

Gbogbo Orílẹ̀-Èdè Ni Ọlọ́run Tẹ́wọ́ Gbà, 4/1

Ibi Ìfarapamọ́sí Kúrò Lọ́wọ́ Ẹ̀fúùfù, 2/15

“Ìgbàlà Jẹ́ Ti Jèhófà” (ètò ìfọkànsin orílẹ̀-èdè ẹni), 9/15

Ìgbà Wo Ni Jèhófà Máa Ń Bù Kún Ìsapá Tí A Fi Taratara Ṣe? 8/1

Ìmọ́tótó, 2/1

Ìnìkanwà, 3/15

Irú Ojú Wo Ló Yẹ Ká Máa Fi Wo Àdánwò? 9/1

Ìwà Títọ́, 8/15

Ìwà Títọ́ Ń Ṣamọ̀nà Àwọn Adúróṣánṣán, (Òwe 11) 5/15

Lílo Ìgbésí Ayé Wa Lọ́nà Tí Inú Jèhófà Dùn Sí, 11/15

“Máa Kọ́ Ara Rẹ,” 10/1

Ǹjẹ́ Bó O Ṣe Ń Kọ́ni Múná Dóko? 7/1

Oríyìn, 11/1

Owú Jíjẹ, 10/15

Ọ̀rọ̀ Àṣírí, 6/15

Pípàdé Pọ̀, 11/15

Rírìn ní Ipa Ọ̀nà Jèhófà, 7/1

Títọ́ Ọmọ Nílẹ̀ Òkèèrè, 10/15

Títọrọ Àforíjì, 11/1

‘Wíwàásù Ọ̀rọ̀ Náà’ Ń Mú Ìtura Wá, 1/15

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Àǹfààní Kíkópa Nínú Ìmúgbòòrò Iṣẹ́ Náà Lẹ́yìn Ogun (F. Hoffmann), 10/1

A Ò Kúrò Nídìí Iṣẹ́ Tá A Yàn fún Wa (H. Bruder), 11/1

Ẹgbẹ́ Àwọn Ará Kárí Ayé fún Mi Lókun (T. Kangale), 7/1

Fífi Ẹ̀mí Ìfara-Ẹni-Rúbọ Sìn (D. Rendell), 3/1

Gbígbin Ìfẹ́ fún Jèhófà Sọ́kàn Àwọn Ọmọ Wa (W. Matzen), 5/1

Ibi Tá A Ti Ń Ṣiṣẹ́ Míṣọ́nnárì Di Ilé Wa (D. Waldron), 12/1

Ìfọkànsin Ọlọ́run Mú Èrè Wá fún Mi (W. Aihinoria), 6/1

Jèhófà Kọ́ Wa Ní Ìfaradà (A. Apostolidis), 2/1

Jèhófà Ti Fún Mi ní “Agbára Tí Ó Ré Kọjá Ìwọ̀n Ti Ẹ̀dá” (H. Marks), 1/1

“Mi Ò Ní Yí Ohunkóhun Padà!” (G. Allen), 9/1

Mo Gbó Mo sì Tọ́ (M. Smith), 8/1

JÈHÓFÀ

Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà, Tó Jẹ́ Ẹni Gidi, 1/15

Lẹ́tà Mẹ́rin Tó Dúró fún Orúkọ Ọlọ́run Wà Nínú Ìtumọ̀ Septuagint, 6/1

Ta Ni Ọlọ́run? 5/15

JÉSÙ KRISTI

Ìbí Jésù, 12/15

LÁJORÍ ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

A Wẹ̀ Wá Mọ́ Láti Jẹ́ Èèyàn fún Iṣẹ́ Àtàtà, 6/1

Àwọn Ìbùkún Ìhìn Rere, 1/1

Àwọn Kristẹni Ń Jọ́sìn ní Ẹ̀mí àti Òtítọ́, 7/15

Àwọn Kristẹni Tí Kì Í Dá sí Tọ̀túntòsì Láwọn Ọjọ́ Ìkẹyìn, 11/1

“Àwọn Ohun Ọlá Ńlá Ọlọ́run” Ń Ru Wá Sókè, 8/1

Àwọn Wo Ni Yóò La Ọjọ́ Jèhófà Já? 5/1

A Ti Mú Wa Gbára Dì fún Iṣẹ́ Olùkọ́ni Ní Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, 2/15

Báwo Ni Òtítọ́ Ti Ṣeyebíye Tó Lójú Rẹ? 3/1

Dídé Ojú Ìwọ̀n Ohun Tí Ọlọ́run Béèrè Ń Gbé Jèhófà Ga, 5/1

Èé Ṣe Tó Fi Yẹ Kó O Ṣe Batisí? 4/1

“Ènìyàn Mìíràn Kò Tíì Sọ̀rọ̀ Báyìí Rí,” 10/15

Ẹ Fi Ìdúróṣinṣin Tẹrí Ba fún Ọlá Àṣẹ Ọlọ́run, 8/1

Ẹ Fi Ìfọkànsìn Ọlọ́run Kún Ìfaradà Yín, 7/15

“Ẹ Kọ Ojú Ìjà sí Èṣù,” 10/15

Ẹ Máa Fi Ọkàn-Àyà Tó Fẹsẹ̀ Múlẹ̀ Ṣinṣin Sin Jèhófà, 4/1

Ẹ Máa Sìn ní Ìfẹ̀gbẹ́kẹ̀gbẹ́, 11/15

‘Ẹ Pọkàn Pọ̀ Ju Ti Àtẹ̀yìnwá Lọ,’ 9/15

“Ẹ Sún mọ́ Ọlọ́run,” 12/15

“Ẹ Tọ́jú Ìwà Yín Kí Ó Dára Lọ́pọ̀lọpọ̀ Láàárín Àwọn Orílẹ̀-Èdè,” 11/1

Fífarada ‘Ẹ̀gún Nínú Ẹran Ara’ 2/15

Gbádùn Ìdákẹ́kọ̀ọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, 12/1

Gbogbo Kristẹni Tòótọ́ Ni Ajíhìnrere, 1/1

Ìdákẹ́kọ̀ọ́ Tó Ń Mú Ká Di Olùkọ́ Tó Pegedé, 12/1

Ìmọ́lẹ̀ Ọlọ́run Ń Lé Òkùnkùn Dà Nù! 3/1

Ire Wa Ni Òfin Ọlọ́run Wà Fún, 4/15

Jèhófà Bìkítà fún Yín, 10/15

Jèhófà Fi Ìmọ́lẹ̀ Bu Ẹwà Kún Àwọn Èèyàn Rẹ̀, 7/1

Jèhófà Jẹ́ Aláìlẹ́gbẹ́ Nínú Rere Ṣíṣe, 1/15

Jèhófà Kórìíra Ìwà Àdàkàdekè, 5/1

Jèhófà Ń Bù Kún Àwọn Onígbọràn, Ó sì Ń Dáàbò Bò Wọ́n, 10/1

Jẹ́ Onígbọràn Bí Òpin Ti Ń Sún Mọ́lé, 10/1

Jíjàǹfààní Inú-Rere-Onífẹ̀ẹ́ Jèhófà, 5/15

“Kì Í Bá Wọn Sọ̀rọ̀ Láìsí Àpèjúwe,” 9/1

Kòṣeémáàní Làwa Kristẹni Jẹ́ fún Ara Wa, 11/15

Kristi Ni Aṣáájú Ìjọ Rẹ̀, 3/15

Máa Fara Wé Olùkọ́ Ńlá Náà, 9/1

Máa Fi Àwọn Ìlànà Ọlọ́run Tọ́ Ìṣísẹ̀ Ara Rẹ, 4/15

Máa Fi Inú-Rere-Onífẹ̀ẹ́ Hàn Sáwọn Aláìní, 5/15

Máa Fi Ìwà Rere Kristẹni Kọ́ Ara Rẹ Àtàwọn Ẹlòmíràn, 6/15

Máa Fi Ohun Tó O Ti Kọ́ Sílò, 9/15

Máa Ṣe Bí Ọba, 6/15

Máa Ṣe Rere Nìṣó, 1/15

“Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn Nígbà Gbogbo,” 8/15

“Mo Fi Àwòṣe Lélẹ̀ fún Yín,” 8/15

Ní Inú Dídùn sí Òdodo Jèhófà, 6/1

Ǹjẹ́ O Ti Rí “Ẹ̀mí Òtítọ́” Náà Gbà? 2/1

Ǹjẹ́ O Wà Lára Àwọn Tí Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́? 2/1

Ògo Jèhófà Tàn Sára Àwọn Èèyàn Rẹ̀, 7/1

Ṣé Lóòótọ́ Lo Gbà Pé Kristi Ni Aṣáájú Wa? 3/15

Wọ́n Fara Da Ẹ̀gún Nínú Ẹran Ara Wọn, 2/15

Wọ́n Ń Bá A Lọ ní Rírìn Nínú Òtítọ́, 7/15

“Yóò sì Sún mọ́ Yín,” 12/15

Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN

Aṣáájú Rere, 3/15

Àwọn Aládùúgbò, 9/1

“Àwọn Amòye Mẹ́ta,” 12/15

Àwọn Ère Ìjọsìn, 7/1

Àwọn Èrò Èké Nípa Ikú, 6/1

“Àwọn Ẹni Mímọ́,” 9/15

Àwọn Ìlànà Ọlọ́run Lè Ṣe Ọ́ Láǹfààní, 2/15

Àwọn Ọmọ Ìyá Kan Náà Tí Ìwà Wọ́n Yàtọ̀ Síra (Kéènì àti Ébẹ́lì), 1/15

Àwọn Ọmọlẹ́yìn Waldo, 3/15

Ayé Ìgbàanì Ṣègbé (Ìkún Omi), 3/1

Ẹ̀bi Ta Ni—Ṣé Ẹ̀bi Rẹ Ni àbí Ti Apilẹ̀ Àbùdá Rẹ? 6/1

Ẹ̀kọ́ Àríkọ́gbọ́n Lára Ẹyẹ Àkọ̀, 8/1

Ẹ̀kọ́ Àríkọ́gbọ́n Látinú Ìtàn Róòmù (àwọn eré ìdárayá oníjà àjàkú akátá), 6/15

Gbẹ́kẹ̀ Lé Ọlọ́run Tó Jẹ́ Ẹni Gidi 1/15

Ìbatisí Clovis, 3/1

Ibo Lo Ti Lè Rí Ìfọ̀kànbalẹ̀? 4/15

Igi Tó “Ń Sunkún” àti “Omijé” Rẹ̀ Tó Wúlò Púpọ̀, 1/15

Ìgbàgbọ́ àti Ọgbọ́n Orí, Ǹjẹ́ Wọ́n Bára Tan? 4/1

Ìgbàgbọ́ Nínú Ohun Asán, 8/1

Ikú, 6/1

Ìlú Tó Wà Lórí Òkè, 2/1

Iná Ọ̀run Àpáàdì, 7/15

Ìṣòro Aráyé, 6/15

Ìṣòro Jíjẹ́ Aláàbọ̀ Ara Kò Ní Sí Mọ́, 5/1

Ìtùnú Nínú Ayé Oníwàhálà, 10/1

Jóṣúà, 12/1

Kíkun Òkú Lọ́ṣẹ, 3/15

Má Ṣe Jẹ́ Kí A Tàn Ọ́ Jẹ, 7/1

Nikodémù, 2/1

Ǹjẹ́ A Nílò Àwọn Ibi Ìjọsìn? 11/15

Ǹjẹ́ Ìwà Kẹ́lẹ́gbẹ́mẹgbẹ́ Lè Tán Láé? 1/1

Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kó O Jẹ́ Ẹni Tó Tutù Lẹ́dàá? 10/1

“Obìnrin Títayọ Lọ́lá” (Rúùtù), 6/15

Ohun Kan Tó Níye Lórí Ju Àwọn Ìṣúra Íjíbítì Lọ (Mósè), 6/15

Ọ̀nà Wo Ló Yẹ Kí Ìsìn Máa Gbà Rí Owó Tó Ń Ná?

Pẹpẹ Kan fún Ọlọ́run Tí Kò Lórúkọ, 7/15

Sátánì—Ṣé Olubi Tó Wà Lóòótọ́ Ni àbí Ẹni Ìtàn Àròsọ Lásán? 10/15

Ṣáfánì àti Ìdílé Rẹ̀, 12/15

Ṣọ́ọ̀ṣì àti Ìjọba ní Ilẹ̀ Ọba Byzantium, 2/15

Tá Ló Yẹ Kó O Jẹ́ Adúróṣinṣin Sí? 8/15

Tertullian, 5/15

“Wò Ó, Ó Lè Dùn Ẹ́ O,” 3/1

Yoga, 8/1