Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2010

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2010

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Inú Ilé Ìṣọ́ 2010

Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Àárín Àwọn Èèyàn Ọlọ́run Lo Ti Lè Rí Ààbò, 6/15

A Batisí Wọn ní Orúkọ Baba, Ọmọ àti Ẹ̀mí Mímọ́, 3/15

Agbo Kan, Olùṣọ́ Àgùntàn Kan, 3/15

Aṣáájú Wa Lóde Òní, 9/15

Àwa Yóò Máa Rìn Nínú Ìwà Títọ́ Wa! 11/15

“Àwọn Olódodo Yóò Máa Tàn Yòò Bí Oòrùn,” 3/15

Bá A Ṣe Lè Rí Ìtura Nínú Àwọn Nǹkan Tẹ̀mí, 6/15

Bí Ìràpadà Ṣe Lè Gbà Wá Là, 8/15

Bí Jésù Ṣe Gbé Òdodo Ọlọ́run Lárugẹ, 8/15

Ẹ Jẹ́ Onítara fún Ìjọsìn Tòótọ́, 12/15

Ẹ Káàbọ̀ sí Ọ̀nà Ìgbésí Ayé Tó Dára Jù Lọ! 2/15

Ẹ Máa Gbé Ìjọ Ró, 6/15

Ẹ Máa Wá “Òdodo Rẹ̀” Lákọ̀ọ́kọ́, 10/15

Ẹ Má Ṣe Kó Ẹ̀dùn-Ọkàn Bá Ẹ̀mí Mímọ́ Jèhófà, 5/15

“Ẹ̀mí àti Ìyàwó Ń Bá A Nìṣó Ní Sísọ Pé: ‘Máa Bọ̀!’” 2/15

‘Ẹ̀mí Ń Wá Inú Àwọn Ohun Ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run,’ 7/15

Ẹ̀yin Arákùnrin, Ẹ Fúnrúgbìn Nípa Tẹ̀mí, Kẹ́ Ẹ Sì Máa Wá Àǹfààní, 5/15

Ẹ̀yin Obìnrin, Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kẹ́ Ẹ Máa Tẹrí Ba fún Ipò Orí? 5/15

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Máa Darí Yín, 11/15

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Má Ṣe Fàyè Gba Ẹ̀mí Ṣohun-Tẹ́gbẹ́-Ń-Ṣe, 11/15

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹ Mú Kí Ìfẹ́ Yín Láti Sin Jèhófà Jinlẹ̀ Sí I, 4/15

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Kí Lẹ Máa Fi Ìgbésí Ayé Yín Ṣe? 11/15

Ẹ̀yin Ọkùnrin, Ṣé Ẹ̀ Ń Tẹrí Ba fún Ipò Orí Kristi? 5/15

Fi Hàn Pé Ojúlówó Ọmọlẹ́yìn Kristi Ni Ẹ́, 1/15

Inú Rere Àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ni fún Wa Láti Jẹ́ Ti Jèhófà, 1/15

Ipa Tí Ẹ̀mí Mímọ́ Ń Kó Nínú Bí Ète Jèhófà Ṣe Ń Ní Ìmúṣẹ, 4/15

“Irú Ènìyàn Wo Ni Ó Yẹ Kí Ẹ Jẹ́!” 7/15

“Ìsinsìnyí Gan-An Ni Àkókò Ìtẹ́wọ́gbà,” 12/15

Ìṣàkóso Jèhófà Ló Dára Jù Lọ! 1/15

Ìṣàkóso Sátánì Máa Forí Ṣánpọ́n, 1/15

Iṣẹ́ Ìsìn! 5/15

Ìṣọ̀kan Àwa Kristẹni Ń Fi Ògo fún Ọlọ́run, 9/15

Ìṣọ̀kan La Fi Ń Dá Ìsìn Tòótọ́ Mọ̀, 9/15

Jèhófà Ni Olúwa Ọba Aláṣẹ Wa! 11/15

Jẹ́ Kí “Òfin Inú-Rere-Onífẹ̀ẹ́” Máa Fi Ìṣọ́ Ṣọ́ Ahọ́n Rẹ, 8/15

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Ya Ara Rẹ Sí Mímọ́ fún Jèhófà? 1/15

Kórè Ìbùkún Yanturu Nípasẹ̀ Ọba Tí Ọlọ́run Ń Fi Ẹ̀mí Rẹ̀ Darí! 12/15

Kọrin sí Jèhófà! 12/15

Máa Fi Taratara Wá Ìbùkún Jèhófà, 9/15

Máa Kó Ipa Tó Jọjú Nínú Ìkórè Tẹ̀mí, 7/15

Máa Lo “Idà Ẹ̀mí” Lọ́nà Tó Jáfáfá, 2/15

Máa Rìn Nípa Ẹ̀mí Kó O sì Mú Ẹ̀jẹ́ Ìyàsímímọ́ Rẹ Ṣẹ, 3/15

‘Máa Sọ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Láìṣojo,’ 2/15

Máa Ṣàkóso Ìbínú Rẹ Kó O Lè “Máa Fi Ire Ṣẹ́gun Ibi,” 6/15

Má Ṣe Máa Wo Àwọn Ohun Tí Kò Ní Láárí! 4/15

Ǹjẹ́ O Máa Ń Mú Ipò Iwájú Nínú Bíbọlá fún Àwọn Tá a Jọ Jẹ́ Onígbàgbọ́? 10/15

Ohun Tí Ọjọ́ Jèhófà Máa Ṣí Payá, 7/15

“Ọ̀kan Ni Aṣáájú Yín, Kristi,” 9/15

Ọ̀rọ̀ Tútù Máa Ń Mú Kí Àjọṣe Wa Pẹ̀lú Àwọn Míì Sunwọ̀n Sí I, 6/15

Ṣé O Máa Ń Mú Kí Àwọn Ìpàdé Ìjọ Gbéni Ró? 10/15

Ṣé Ò Ń Tọ Kristi Lẹ́yìn Nígbà Gbogbo? 4/15

Ta Ló Lè Dá Àwọn Tó Ń Kígbe fún Ìrànlọ́wọ́ Nídè? 8/15

“Ta Ni Ó Ti Wá Mọ Èrò Inú Jèhófà?” 10/15

ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

Ayẹyẹ Ìkẹ́kọ̀ọ́yege Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì, 2/1, 8/1

Bulgaria, 9/15

Èèyàn Kì Í Dàgbà Jù Láti Sin Ọlọ́run (Sípéènì), 12/15

Erékùṣù Jíjìnnà Réré ní Àríwá Ọsirélíà, 5/1

Èrò Wọn Nípa Àwọn Ẹlẹ́sìn Ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ Tó Ń Jọ́sìn Pa Pọ̀, 6/1

Grenada, 9/1

Gbogbo Èèyàn La Pè (Bẹ́tẹ́lì), 8/15

Gbọ̀ngàn Ìjọba, 5/1

Haiti, 12/1

Ìpàdé Ọdọọdún, 6/15

Ìrántí Ikú Kristi, 3/1

Iṣẹ́ Ìwàásù àti Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Nílẹ̀ Áfíríkà, 3/1

Ìwé Táá Jẹ́ Káwọn Ọ̀dọ́ Rántí Ẹlẹ́dàá Wọn (Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé, Apá Kejì), 2/15

‘Ó Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Mi Wọni Lọ́kàn (ìwé kékeré Nations), 10/15

‘Ọrẹ Ẹbọ fún Jèhófà’ (àwọn ọrẹ), 11/15

Papua New Guinea, 3/1

South Africa, 6/1

Ṣé Wọ́n Máa Ń Fi Iṣẹ́ Ìyanu Ṣèwòsàn? 10/1

Wíwà Lójúfò (Finland), 7/15

BÍBÉLÌ

Ìdí Tí Mátíù Fi Sọ Pé Jeremáyà Ló Sọ Ọ̀rọ̀ Kan Tó Wà Nínú Ìwé Sekaráyà, 12/1

Ìdí Tí O Fi Lè Gbẹ́kẹ̀ Lé Àwọn Ìwé Ìhìn Rere, 3/1

Ìsíkíẹ́lì 18:20 àti Ẹ́kísódù 20:5 kò ta kora, 3/15

Ǹjẹ́ Ó Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Orílẹ̀-Èdè Ísírẹ́lì Òde Òní? 11/1

Ǹjẹ́ Ó Sọ Gbogbo Òtítọ́ Nípa Jésù fún Wa? 4/1

Òǹtẹ̀wé Ìjímìjí Kan Gbé E Lárugẹ, 7/1

Ó Ń Yí Ìgbésí Ayé Èèyàn Pa Dà, 2/1, 5/1, 8/1, 11/1

Ọ̀nà Méje Téèyàn Lè Gbà Jàǹfààní Látinú Bíbélì Kíkà, 7/1

Ṣé Ó Ní Ìmísí Ọlọ́run? 3/1

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

Àdúrà, 10/1

Adúróṣinṣin Nígbà Ìdánwò (Pétérù), 1/1

Àna, 2/1

Àwíjàre, 10/15

Àwọn Ọ̀nà Téèyàn Lè Gbà Ní Ìtẹ́lọ́rùn, 11/1

Àwọn Tí Ọkọ Tàbí Aya Wọn Kú, 5/1

Bá A Ṣe Lè Tọ́ Ọmọ Kan Di Ẹni Tó Dáńgájíá, 5/1

Bá Ò Ṣe Ní Pàdánù Ojúure Ọlọ́run Bí Ìyípadà Bá Tiẹ̀ Dé Bá Wa, 3/15

Bá Ọmọ Rẹ Sọ̀rọ̀ Nípa Ìbálòpọ̀, 11/1

Bó O Ṣe Lè Fara Dà Á bí Ọkọ Tàbí Aya Rẹ Bá Já Ẹ Jù Sílẹ̀, 6/15

Borí Èrò Òdì, 10/1

Bọ̀wọ̀ fún Àwọn Àgbàlagbà, 5/15

Dúró Lórí Ohun Tó O Gbà Gbọ́! (Jeremáyà), 5/1

‘Ẹ Jẹ́ Pípé bí Baba Yín Ọ̀run Ti Jẹ́ Pípé,’ 11/15

Ẹ̀kọ́ Nípa Àánú Ọlọ́run (Jónà), 3/1

“Ẹ̀tọ́ Àwọn Ọmọdé Láti Mọ Ọlọ́run,” 2/15

Ìgbatẹnirò fún Àwọn Òbí Tó Ń Dá Tọ́mọ, 12/1

Jẹ́ Kí Ìgbé Ayé Rẹ Ojoojúmọ́Máa Fi Ògo fún Ọlọ́run, 1/15

Jẹ́ Olóòótọ́ ní Gbogbo Ìgbà, 3/1

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Máa Dé Lásìkò? 8/15

Kí Ni Ọmọ Rẹ Máa Sọ? 12/15

Kọ́ Àwọn Ọmọ Láti Nífẹ̀ẹ́ sí Ìwé Kíkà àti Ìkẹ́kọ̀ọ́, 7/15

Máa Dènà Ìpolongo Èké Sátánì, 2/15

‘Máa Fi Ara Rẹ fún Kíkọ́ni,’ 7/15

“Má Fòyà. Èmi Fúnra Mi Yóò Ràn Ọ́ Lọ́wọ́,” 7/15

Máa Lo Agbára Ìwòye, 5/15

Má Ṣe Jẹ́ Kí Èrò Àwọn Èèyàn Máa Darí Rẹ, 8/15

Ní ‘Ọkàn-àyà Tó Mọ́,’ 3/15

Ó Kọ́ Ìdáríjì Lọ́dọ̀ Ọ̀gá Rẹ̀ (Pétérù), 4/1

Ọdún Àkọ́kọ́ Ìgbéyàwó, 8/1

Ọkùnrin Onírẹ̀lẹ̀ àti Onígboyà (Jónà), 1/1

Ọ̀ràn Gbígbé Pa Pọ̀, 2/15

Ran Àwọn Ọ̀dọ́ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Mọ Ètò Jèhófà Dunjú, 10/15

Ran Àwọn Ọmọ Lọ́wọ́ Láti Kojú Àwọn Ìṣòro, 1/15

Rí Àwọn Ọ̀rẹ́ Tó Jẹ́ Adúróṣinṣin, 7/1

Ṣé Ìwà Àìṣòótọ́ Ni? 6/1

Ṣé Ó Yẹ Kó O Máa Pa Sábáàtì Mọ́? 2/1

Ṣèrànwọ́ fún Ọ̀rẹ́ Tó Ń Ṣàìsàn, 7/1

“Títí Ikú Yóò Fi Yà Wá,” 3/1

Títọ́jú Ìbátan Tó Ń Ṣàìsàn, 5/15

Títún Ìrìbọmi Ṣe, 2/15

Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú, 11/1

Wà ní “Àlàáfíà” àti Láìséwu, 4/15

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Àdánwò Mú Ká Túbọ̀ Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà (A. Dello Stritto), 4/15

‘Àwọn Ohun Tó Ṣe Ti Bá A Lọ ní Tààràtà’ (T. Jaracz), 11/15

Bí Òtítọ́ Bíbélì Ṣe Lágbára Tó (V. Fraese), 12/15

Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà (E. Schmidt), 9/1

Mo Sìn Lásìkò Ìmúgbòòrò (H. Harris), 9/15

Ọlọ́run Jẹ́ “Olùṣe Àwọn Ohun Ńlá” (M. Raj), 12/1

Ọwọ́ Mi Dí Nínú Ètò Jèhófà (V. Zubko), 10/15

JÈHÓFÀ

Fẹ́ Kó O Wà ní “Àlàáfíà” àti Láìséwu, 4/15

Fún Wa Lómìnira Láti Ṣe Ohun Tó Wù Wá, 9/1

“Gbé Ọmọkùnrin Rẹ” (a jí ọmọkùnrin kan dìde), 8/1

Ìdúróṣinṣin, 6/1

‘Ìjọba Rẹ Yóò Fẹsẹ̀ Múlẹ̀’ (Dáfídì), 4/1

Kì Í Ṣe Ojúsàájú, 9/1

Kí Nìdí Tó Fi Fẹ́ Fún Aráyé Ní Ìyè Àìnípẹ̀kun? 1/1

Kọjú Ìjà sí Àwọn Ọmọ Kénáánì, 1/1

Mọ Ọkàn-Àyà, 12/1

Ń Gbọ́ Igbe Àwọn Ẹni Rírẹlẹ̀, 11/15

Nígbà Tí ‘Ọkàn Tí Ó Ní Ìròbìnújẹ́ Tí Ó sì Wó Palẹ̀’ Bá Tọrọ Ìdáríjì, 5/1

Ǹjẹ́ Gbogbo Èèyàn Ló Láǹfààní Kan Náà Láti Mọ? 8/1

Ǹjẹ́ O Kà Á sí Bàbá Rẹ? 2/15

Ǹjẹ́ Ó Lè Kẹ́dùn? 2/1

Ǹjẹ́ O Mọ Orúkọ Ọlọ́run? 7/1

Ǹjẹ́ Ó Ní Ìbẹ̀rẹ̀? 7/1

Ń Mú Ìlérí Ṣẹ, 1/1

‘Ń Wo Ọkàn-Àyà,’ 3/1

“Olùgbọ́ Àdúrà,” 10/1

Orúkọ Nínú Tẹ́ńpìlì Íjíbítì, 5/1

Rere Ló Ń Wò, 7/1

Ṣé Ò Ń Jẹ́ Kí Jèhófà Bi Ẹ́ Ní Ìbéèrè, 4/15

Ṣé Ọlọ́run Ti Pa Wá Tì? 5/1

“Yóò Jẹ́ Kí O Rí Òun” (1Kr 28:9), 11/1

JÉSÙ KRISTI

Àwọn Amòye Tó Wá Kí I, 12/1

Àwọn Tó Kọ̀wé Nípa Jésù, 6/1

Bí A Ṣe Lè Tẹ̀ Lé E, 5/1

Dárí Ẹ̀ṣẹ̀ Ji Obìnrin Kan, 8/15

Ìdí Tá A Fi Pè É Ní Kristi, 4/1

Ìdí Tí Kò Fi Kánjú, 8/1

Ìdí Tí Wọ́n Fi Kọ̀ Ọ́, 12/1

Káfíńtà, 8/1

Kẹ́kọ̀ọ́ Láti Jẹ́ Onígbọràn, 4/1

Kò Lọ́wọ́ Nínú Ìṣèlú, 7/1

Kọ́ni Nípa Àwọn Áńgẹ́lì, 11/1

Kọ́ni Nípa Bí A Ṣe Lè Láyọ̀, 8/1

Kọ́ni Nípa Ìjọsìn Tòótọ́, 2/1

Ǹjẹ́ Ó Bá Àwọn Àpọ́sítélì Tan? 9/1

Ǹjẹ́ Ó Bá Jòhánù Oníbatisí Tan? 9/1

Ó Gbé Ayé Rí, 4/1

Ọkùnrin Tó Ṣe Ohun Tó Ta Yọ Fáráyé, 4/1

Ṣé Irọ́ Ni àbí Òótọ́? 4/1

Ṣé Òun Ni Máíkẹ́lì Olú Áńgẹ́lì? 4/1

Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN

Aáwọ̀ Tó Wà Láàárín Àwọn Júù Àtàwọn Ará Samáríà, 10/1

Adẹ́tẹ̀ Rí Ìwòsàn Gbà (Náámánì), 11/1

Agbọ́tí Ọba, 7/1

A Kò Fìyà Jẹ Áárónì Nítorí Pé Ó Ṣe Ère Ọmọ Màlúù, 5/15

Àkọ́bí Tó Jẹ́ Ọkùnrin, 5/1

Àṣírí Tí O Lè Sọ fún Ẹlòmíì, 12/1

Àwọn Agbèjà Ìgbàgbọ́, 6/1

Àwọn Akóló Ìkó-Ìwé-Mímọ́-Sí, 5/1

“Àwọn Àpá Àmì Ti Ẹrú Jésù” (Ga 6:17), 11/1

“Àwọn Ibi Gíga,” 8/1

“Àwọn Ọkùnrin Ọlọ́bẹ Aṣóró” (Iṣe 21:38), 3/1

Àwọn Wo Ló Ń Gbé ní Ọ̀run? 12/1

Básámù Gílíádì, 6/1

Ẹ̀kọ́ Ìsìn Calvin, 9/1

Ẹ̀mí Mímọ́, 10/1

Ẹnubodè Ìlú, 6/1

Ẹran Tí Wọ́n Fi Rúbọ Sáwọn Òrìṣà, 10/1

Ẹ̀ṣẹ̀, 6/1

Fífi Èdè Fọ̀, 10/1

Háránì Ìlú Àtijọ́ Tó Kún fún Ìgbòkègbodò, 5/15

Ibo Ni Kéènì Ti Rí Ìyàwó Rẹ̀? 9/1

Ibo Ni Párádísè Tí Bíbélì Sọ Máa Wà? 12/1

Ìdí Táwọn Èèyàn Fi Ń Hùwà Ibi, 9/1

Ìjọba Tó Máa Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà, 10/1

Ilé Tí Wọ́n Ń Gbé (àwọn Kristẹni àkọ́kọ́bẹ̀rẹ̀), 1/1

Ìrìn Àjò Ayé Àtijọ́ Tó Kọjá Òkun Mẹditaréníà, 3/1

Ìrìn Àjò sí Apá Ibi Jíjìnnà Jù Lọ ní Ilẹ̀ Ayé, 11/1

Irú Ọtí Tí Wọ́n Máa Ń Ṣe Nígbà Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì, 2/1

“Ìtọ́wọ̀ọ́rìn Aláyọ̀ Ìṣẹ́gun” (2Kọ 2:14-16), 8/1

Jíjẹ́wọ́ Ẹ̀ṣẹ̀, 9/1

Máàkù ‘Wúlò fún Iṣẹ́ Ìránṣẹ́,’ 3/15

Mẹ́talọ́kan, 2/1

Ǹjẹ́ Àwọn Èèyàn ní Àkókò Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì Pẹ́ Láyé Gan-an? 12/1

Ǹjẹ́ Oúnjẹ àti Àlùmọ́ọ́nì Inú Ilẹ̀ Máa Tó? 3/1

Ó Gbàdúrà Àtọkànwá sí Ọlọ́run (Hánà), 7/1

Ojú Tí Àwọn Kristẹni Ọ̀rúndún Kìíní Fi Wo Òrìṣà Àwọn Ará Róòmù, 5/15

Ojú Tí Ọlọ́run Fi Ń Wo Ọtí Mímu, 1/1

Ó “Ń Bá A Lọ Ní Dídàgbà Lọ́dọ̀ Jèhófà” (Sámúẹ́lì), 10/1

“Òṣìṣẹ́ ní Ilé” (Tit 2:5), 2/1

Ó Ṣòro Láti Tukọ̀ Nígbà Ayé Pọ́ọ̀lù, 2/1

‘Ọjọ́ Èèyàn Yóò Jẹ́ Ọgọ́fà Ọdún’ (Jẹ 6:3), 12/15

Ọ̀nà Tí Pọ́ọ̀lù Gbà Nígbà Tó Rìnrìn Àjò (Ọ̀nà Ápíà), 1/1

Rèbékà, 2/1

Sínágọ́gù, 4/1

Ṣé Àwọn Èèrà Máa Ń Pèsè Oúnjẹ Sílẹ̀ Nígbà Ẹ̀ẹ̀rùn? 7/1

Ṣé Àwọn Ìràwọ̀ Ń Darí Ìgbésí Ayé Rẹ? 6/1

Ṣé Ayé Máa Pa Rẹ́? 1/1

Ṣé Gbogbo Èèyàn Rere Ló Ń Lọ sí Ọ̀run? 2/1

Ṣé Ibi Ààbò fún Àwọn Ọ̀daràn Ni Ìlú Ààbò Jẹ́? 11/1

Ṣé Òkú Lè Ran Alààyè Lọ́wọ́? 1/1

Ṣé Òpin Ti Sún Mọ́lé? 8/1

Ṣé Ó Yẹ Kí N Dara Pọ̀ Mọ́ Ẹ̀sìn Kan? 11/1

Ṣọ́ra fún Ẹ̀tàn, 9/1

‘Wáìnì Tuntun, Ògbólógbòó Àpò Awọ’ (Lu 5:37, 38), 3/1

Wàláà Ìkọ̀wé (Lu 1:63), 1/1

Wúrà Ófírì, 6/1