Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ẹ̀kọ́ Bíbélì

Ẹ̀kọ́ Bíbélì

Ẹ̀kọ́ Bíbélì

ỌMỌ ỌDÚN MẸ́TA ÀTI ÀWỌN TÍ KÒ TÓ BẸ́Ẹ̀

Ta ló dá ayé?

Ta ló dá òkun?

Ta ló dá ìwọ àti èmi?

Ta ló dá labalábá pẹ̀lú ìyẹ́ rẹ̀ aláràbarà?

Jèhófà Ọlọ́run ló dá ohun gbogbo Ìṣípayá 4:11

IṢẸ́ ÒBÍ

Kọ́ ọmọ rẹ:

Kí ni orúkọ Ọlọ́run?

Ibo ni Jèhófà ń gbé?

Kí ni Jèhófà dá?

Ní kí ọmọ rẹ tọ́ka sí:

Àwọn ìràwọ̀ Ojú ọ̀run Oòrùn

Ọkọ̀ ojú omi Ayé Ilé

Òkun Labalábá