Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ẹ̀kọ́ Bíbélì

Ẹ̀kọ́ Bíbélì

Ẹ̀kọ́ Bíbélì

ỌMỌ ỌDÚN MẸ́TA ÀTI ÀWỌN TÍ KÒ TÓ BẸ́Ẹ̀

Wo àwọn ẹranko tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọkọ̀ Nóà.

Èwo ló máa ń ké mùúù, èwo ló sì máa ń gbó?

Gbogbo ẹranko, àwọn tó kéré àtàwọn tó tóbi, ọkọ̀ áàkì gba gbogbo wọn là. Jẹ́nẹ́sísì 7:7-10; 8:15-17

IṢẸ́ ÒBÍ

Ní kí ọmọ rẹ tọ́ka sí:

Ọkọ̀ Áàkì Béárì Ajá

Erin Àgùnfọn Kìnnìún

Ọ̀bọ Ẹlẹ́dẹ̀ Àgùntàn

Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ abilà Òṣùmàrè Igi

Ké bí àwọn ẹranko yìí ṣe ń ké:

Ajá Kìnnìún Ọ̀bọ

Ẹlẹ́dẹ̀ Àgùntàn