Atọ́ka àwọn àkòrí inú Ilé Ìṣọ́ Ẹ̀dà Tó Wà Fún Ìkẹ́kọ̀ọ́ ti ọdún 2013
Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Ẹ Máa Bá Ara Yín Sọ̀rọ̀ Kẹ́ Ẹ Lè Túbọ̀ Ṣera Yín Lọ́kan, 5/15
Ẹ Máa Gba Ti Ara Yín Rò Kẹ́ Ẹ sì Máa fún Ara Yín Ní Ìṣírí, 8/15
Ẹ̀yin Olùṣọ́ Àgùntàn, Ẹ Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Ńlá Náà, 11/15
Máa Ṣe Ìpinnu Tó Dára Kó O Má Bàa Pàdánù Ogún Tẹ̀mí Rẹ, 5/15
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
Àwọn Àpéjọ Àgbègbè ‘Òtítọ́ Ni Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run!’ 5/1
Wọ́n Dúró Ṣinṣin ní “Wákàtí Ìdánwò” (Ogun Àgbáyé Kìíní), 5/15
BÍBÉLÌ
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
JÈHÓFÀ
JÉSÙ KRISTI