Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2018

Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ àti Jí! 2018

Ó ń tọ́ka sí ìwé ìròyìn tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

  • 1918​—Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn, Oct.

  • Àsọyé Mú Kí Ìhìn Rere Tàn Kálẹ̀ (Ireland), Feb.

  • Ẹ̀bùn Wo La Lè Fún Jèhófà? (ọrẹ), Nov.

  • Ẹ̀yin Àgbàlagbà​—Jèhófà Mọyì Yín, Sept.

  • Ẹ̀yin Tá A Yàn Sípò​—Ẹ Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Tímótì, Apr.

  • Ìkórè Yìí Mà Pọ̀ O! (Ukraine), May

  • Iṣẹ́ Fífúnrúgbìn Ìjọba Náà Bẹ̀rẹ̀ (Pọ́túgà), Aug.

  • Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn ní Madagásíkà, Jan.

  • Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn ní Myanmar, July

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

  • A Jẹ́ ti Jèhófà, July

  • A Máa Láyọ̀ Tá A Bá Jẹ́ Ọ̀làwọ́, Aug.

  • “Àá Pàdé ní Párádísè!” Dec.

  • Aájò Àlejò Ṣe Pàtàkì Gan-An! Mar.

  • Alágbára Ńlá Ni Jèhófà, Síbẹ̀ Ó Ń Gba Tẹni Rò, Sept.

  • Aláyọ̀ Ni Àwọn Tó Ń Sin “Ọlọ́run Aláyọ̀,” Sept.

  • Bá A Ṣe Lè Ní Òmìnira Tòótọ́, Apr.

  • Báwo Ni Ìbáwí Ṣe Ń Fi Hàn Pé Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Wa? Mar.

  • “Bí Ẹ Bá Mọ Nǹkan Wọ̀nyí, Aláyọ̀ Ni Yín Bí Ẹ Bá Ń Ṣe Wọ́n,” Sept.

  • Bí Ẹ̀yin Ọ̀dọ́ Ṣe Lè Gbádùn Ìgbésí Ayé Yín, Dec.

  • Bó O Ṣe Lè Ní Ìbàlẹ̀ Ọkàn Láìka Ìyípadà Èyíkéyìí Sí, Oct.

  • Ẹ Jẹ́ “Kí Ìmọ́lẹ̀ Yín Máa Tàn” Kẹ́ Ẹ Lè Fògo fún Jèhófà, June

  • Ẹ Máa Fìfẹ́ Gbé Àwọn Míì Ró, Sept.

  • “Èmi Yóò Máa Rìn Nínú Òtítọ́ Rẹ,” Nov.

  • Ẹ̀yin Òbí, Ṣé Ẹ̀ Ń Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣèrìbọmi? Mar.

  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́​—Ẹ Dúró Gbọn-In Lòdì sí Èṣù, May

  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ẹlẹ́dàá Yín Fẹ́ Kẹ́ Ẹ Láyọ̀, Dec.

  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ṣé Ìjọsìn Jèhófà Ló Gbawájú ní Ìgbésí Ayé Yín? Apr.

  • ‘Fetí sí Ìbáwí Kó O sì Di Ọlọ́gbọ́n,’ Mar.

  • Fi Ọwọ́ Pàtàkì Mú “Ohun Tí Ọlọ́run Ti So Pọ̀,” Dec.

  • Fọkàn Tán Kristi Tó Jẹ́ Aṣáájú Wa, Oct.

  • Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Kó O Lè Wà Láàyè! Nov.

  • Ìfẹ́ Wo Ló Ń Mú Kéèyàn Ní Ojúlówó Ayọ̀? Jan.

  • “Ìjọba Mi Kì Í Ṣe Apá Kan Ayé Yìí,” June

  • Ìrántí Ikú Kristi Ń Mú Ká Wà Níṣọ̀kan, Jan.

  • Ìrìbọmi​—Ohun Tó Yẹ Kí Gbogbo Kristẹni Ṣe, Mar.

  • Ìsinsìnyí Ló Yẹ Ká Máa Fún Ara Wa Níṣìírí Ju ti Ìgbàkigbà Rí Lọ, Apr.

  • Ìyàtọ̀ Tó Wà Láàárín Àwọn Tó Ń Sin Ọlọ́run Àtàwọn Tí Kò Sìn Ín, Jan.

  • Jẹ́ Onígbọràn Kó O sì Nígbàgbọ́ Bíi Ti Nóà, Dáníẹ́lì àti Jóòbù, Feb.

  • Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Tó Ń “So Èso Pẹ̀lú Ìfaradà,” May

  • ọ́Jọ́sìn Jèhófà, Ọlọ́run Tí Ń Fúnni Ní Òmìnira, Apr.

  • Ká Jẹ́ Ọ̀kan Bí Jèhófà àti Jésù Ṣe Jẹ́ Ọ̀kan, June

  • Kí Ló Túmọ̀ Sí Pé Kéèyàn Jẹ́ Ẹni Tẹ̀mí? Feb.

  • Kí Nìdí Tá A Fi Ń “Bá A Nìṣó ní Síso Èso Púpọ̀”? May

  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Fún Ẹni Tó Ni Ohun Gbogbo Ní Nǹkan? Jan.

  • Má Ṣe Máa Fi Ìrísí Dáni Lẹ́jọ́, Aug.

  • Máa Bá Jèhófà Ṣiṣẹ́ Lójoojúmọ́, Aug.

  • Máa Fi Àwọn Òfin àti Ìlànà Jèhófà Kọ́ Ẹ̀rí Ọkàn Rẹ, June

  • Máa Fi Òtítọ́ Kọ́ni, Oct.

  • Máa Fúnni Níṣìírí Bíi Ti Jèhófà, Apr.

  • Máa Gba Tàwọn Míì Rò Bíi Ti Jèhófà, Sept.

  • Máa Rí Àrídájú Ọ̀rọ̀, Aug.

  • Máa Sọ Òtítọ́, Oct.

  • Mọ Ọ̀tá Rẹ, May

  • “Ó Ń Fi Agbára fún Ẹni Tí Ó Ti Rẹ̀,” Jan.

  • Ojúure Ta Lò Ń Wá? July

  • “Ra Òtítọ́, Má sì Tà Á,” Nov.

  • Sapá Láti Túbọ̀ Di Ẹni Tẹ̀mí, Feb.

  • Ṣé Jèhófà Lo Tẹjú Mọ́? July

  • Ṣé O Mọ Jèhófà Dáadáa Bíi Ti Nóà, Dáníẹ́lì àti Jóòbù? Feb.

  • Ṣé Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wo Nǹkan Ni Ìwọ Náà Fi Ń Wò Ó? Nov.

  • Ta Ló Ń Darí Èrò Rẹ? Nov.

  • “Ta Ni Ó Wà ní Ìhà Ọ̀dọ̀ Jèhófà?” July

BÍBÉLÌ

  • Jẹ́ Kí Ìkẹ́kọ̀ọ́ Gbádùn Mọ́ Ẹ Kó sì Ṣe Ẹ́ Láǹfààní, July

ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ

  • Àwọn wo ni àwọn Olóore tí Jésù mẹ́nu kàn? Nov.

  • Báwo ni a ṣe gba Pọ́ọ̀lù ‘lọ sí ọ̀run kẹta’ àti “sínú párádísè”? (2Kọ 12:​2-4), Dec.

  • Kí nìdí tá a fi máa ń yàwòrán Pọ́ọ̀lù bí ẹni tó pá lórí? Mar.

  • Kí nìdí tá a fi ṣàtúnṣe sí Sáàmù 144:​12-15? Apr.

  • Kí nìdí tí kò fi yẹ ká máa gbé àwọn ìtẹ̀jáde wa sórí ìkànnì míì? Apr.

  • Ṣé wọ́n lè gbé ìgbìmọ̀ onídàájọ́ dìde táwọn méjì tí kì í ṣe tọkọtaya bá sun inú ilé kan náà mọ́jú? July

ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI

  • Àlàáfíà​—Báwo Lo Ṣe Lè Ní In? May

  • Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Kí Àwọn Èèyàn, June

  • Ìdùnnú​—Ànímọ́ Tí Ọlọ́run Ń Fúnni, Feb.

  • Inú Rere​—Ànímọ́ Kan Tó Yẹ Kó Hàn Nínú Ọ̀rọ̀ àti Ìṣe Wa, Nov.

  • Ìpamọ́ra​—Fífaradà Á Pẹ̀lú Ìrètí, Aug.

  • Máa Fàánú Hàn sí Àwọn Èèyàn, July

  • ‘Olódodo Yóò Máa Yọ̀ Nínú Jèhófà,’ Dec.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

  • Jèhófà Bù Kún Ìpinnu Tí Mo Ṣe (C. Molohan), Oct.

  • Jèhófà Dá Mi Lọ́lá Bí Mo Tiẹ̀ Jẹ́ Ọmọ Tálákà (S. Herd), May

  • Jèhófà Fi Inú Rere Hàn sí Wa (J. Bockaert), Dec.

  • Jèhófà Ò Já Mi Kulẹ̀ Rí (E. Bright), Mar.

  • Jèhófà Tù Mí Nínú (E. Bazely), June

  • Mo Pinnu Pé Mi Ò Ní Juwọ́ Sílẹ̀ (M. Danyleyko), Aug.

  • Ohun Gbogbo Ṣeé Ṣe Lọ́dọ̀ Jèhófà (B. Berdibaev), Feb.

Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN

  • Ǹjẹ́ O Mọ Ohun Tí Aago Sọ? (Àsìkò tí wọ́n ń kọ Bíbélì), Sept.

  • Ó Pàdánù Ojú Rere Ọlọ́run (Rèhóbóámù), June

  • Ọkàn Sítéfánù Balẹ̀ Nígbà Tí Wọ́n Ṣenúnibíni sí I, Oct.

  • Ṣé Wọ́n Fi Àwọn Ìlànà Inú Òfin Mósè Yanjú Èdèkòyédè? Jan.

ILÉ ÌṢỌ́ TÁ À Ń FI SÓDE

  • Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Iwájú? No. 2

  • Ṣé Bíbélì Ṣì Wúlò Lóde Òní? No. 1

  • Ṣé Ọlọ́run Bìkítà Nípa Rẹ? No. 3

JÍ!

  • Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀, No. 3

  • Ohun Méjìlá Tó Ń Mú Kí Ìdílé Láyọ̀, No. 2

  • Ohun Tó Ń Fúnni Láyọ̀, No. 1