Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

O Lè Sún Mọ́ Ọlọ́run

O Lè Sún Mọ́ Ọlọ́run

ÀWỌN KAN RÒ PÉ . . .

Kò sí bá a ṣe lè sún mọ́ Ọlọ́run, torí pé kò rí tiwa rò, ó ti jìnnà jù sí wa àti pé ẹni mímọ́ ni.

BÍBÉLÌ SỌ PÉ

“Ẹ sún mọ́ Ọlọ́run, yóò sì sún mọ́ yín.”​—Jákọ́bù 4:8.

“Ẹ kó gbogbo àníyàn yín lé e, nítorí ó bìkítà fún yín.”​—1 Pétérù 5:7.

BÁWO LA ṢE LÈ SÚN MỌ́ ỌLỌ́RUN?