Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

September 4-10

Ẹ́SÍTÀ 1-2

September 4-10
  • Orin 137 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bíi Ti Ẹ́sítà”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • Ẹst 2:5—Ẹ̀rí wo ló fi hàn pé ẹni gidi tó gbé láyé ni Módékáì tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀? (w22.11 31 ¶3-6)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ẹst 1:​13-22 (th ẹ̀kọ́ 10)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 106

  • Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ Nípa Ìrísí: (5 min.) ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, béèrè pé: Kí nìdí tó fi lè ṣòro láti ní èrò tó tọ́ nípa ìrísí wa?

    Báwo ni ìlànà tó wà ní 1 Pétérù 3:​3, 4 ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ láti ní èrò tó tọ́ nípa ara wa?

  • Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù September.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 56 àti àlàyé ìparí ìwé 6 àti 7

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 101 àti Àdúrà