Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ó Lo Àṣẹ Tó Ní Láti Ran Àwọn Èèyàn Ọlọ́run Lọ́wọ́

Ó Lo Àṣẹ Tó Ní Láti Ran Àwọn Èèyàn Ọlọ́run Lọ́wọ́

Módékáì wà ní ipò àṣẹ (Ẹst 9:4; it-2 432 ¶2)

Ó dá àjọyọ̀ ọdọọdún sílẹ̀ láti máa fi bọlá fún Jèhófà (Ẹst 9:​20-22, 26-28; it-2 716 ¶5)

Ó ṣiṣẹ́ fún ire àwọn èèyàn Ọlọ́run (Ẹst 10:3)

Lónìí, àwọn alábòójútó nínú ètò Ọlọ́run máa ń ṣe gbogbo ohun tí wọ́n lè ṣe láti tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Módékáì.—cl 101-102 ¶12-13.