Re listi urun ti o winọrọn

Re listi urun ti o wi iwe we

KA DO UDOẸYE OLELE KRAIST

Ọsin-Agutan ti O Ka Ṣe Uṣẹ gbẹ Ọsan Ira Jihova

Ọsin-Agutan ti O Ka Ṣe Uṣẹ gbẹ Ọsan Ira Jihova

Irẹye gidijẹ ee ka gba eju ti o san ṣọn aghan ti o nẹ aṣẹ. Ee ṣe ọfọ aghan ti o ro wẹrẹ. Irẹye gidijẹ nẹ lo aṣẹ ti aghan nẹ ni ewe ti ee jọ rẹn. (Maik 7:3) Ẹnẹ jọlọ yọ gin a kọ aghan ẹghaarẹ ti o wi ujọ biri aghan te wa lo aṣẹ ti aghan nẹ gbẹ ọsan ira Jihova.—Ẹst 10:3; Mat 20:25, 26.

Aghan ẹghaarẹ ni ujọ ṣe ukanrin kuri aghan ti o nẹ aṣẹ ni ẹye we. Aghan ka ṣe uṣẹ aghan teri wuwu ti aghan nẹ gbẹ Jihova biri ira ro. (Jọn 21:16; 1Pit 5:1-3) Ni abẹ sisin Jisọs, ọsin-agutan ghaan ka mu utiẹyin gbẹ omere ọkan-ọkan ni ujọ gba man gin aghan wi oriọghan ni ẹbi Jihova, biri gba tama a. Aghan numuara gba mu ẹkọ gbẹ agutan Jihova, biri gba mu utiẹyin ṣi ni ikobo ẹdigbukun ma ṣi wẹrẹ ni ira ti ibajẹ ma guo ubo. Wo ma fẹ utiẹyin, maa jẹ di anọ mu ẹ gba biri ẹghaarẹ ọkan ni ujọ rẹ fọ?—Jem 5:14.

GHO VIDIO WE ỌSIN-AGUTAN TI O KA BEJUTO ỌGHỌRIGHỌ AGUTAN, KURO DI AGHAN GBA IWANRAN NI UBIRỌ GHAAN TI O LELE:

  • Bokọ Mariana te jẹ ere kuri utiẹyin ti aghan ẹghaarẹ mu ṣi?

  • Bokọ Elias te jẹ ere kuri utiẹyin ti aghan ẹghaarẹ mu ṣi?

  • Ti wo gba gho vidio we kuro, eju bokọ wo gba ṣọn uṣẹ ti aghan ẹghaarẹ ka ṣe?