Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ṣọ́ra Fáwọn Ọ̀rọ̀ Tí Kì Í Ṣòótọ́

Ṣọ́ra Fáwọn Ọ̀rọ̀ Tí Kì Í Ṣòótọ́

Torí pé àgbàlagbà ni Élífásì, ó sì gbọ́n, ọ̀pọ̀ èèyàn gbà pé ọ̀rọ̀ tó bá sọ máa ṣeé gbára lé (Job 4:1; it-1 713 ¶11)

Àwọn ẹ̀mí èṣù mú kí Élífásì sọ ọ̀rọ̀ tó máa kó ìrẹ̀wẹ̀sì bá Jóòbù (Job 4:​14-16; w05 9/15 26 ¶2)

Bó tiẹ̀ jẹ́ pé òótọ́ díẹ̀ wà nínú ọ̀rọ̀ tí Élífásì sọ, àmọ́ ìtumọ̀ míì ló fún un (Job 4:19; w10 2/15 19 ¶5-6)

Nínú ayé tí Sátánì ń ṣàkóso yìí, àwọn èèyàn máa ń tan àwọn ọ̀rọ̀ tí kì í ṣòótọ́ kálẹ̀.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé mo máa ń fara balẹ̀ ronú lórí ohun tí mo bá gbọ́ kí n lè mọ̀ bóyá ó jóòótọ́?’—mrt 32 ¶13-17.