Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ohun Mẹ́ta Táá Jẹ́ Ká Ní Ọgbọ́n, Kó sì Ṣe Wá Láǹfààní

Ohun Mẹ́ta Táá Jẹ́ Ká Ní Ọgbọ́n, Kó sì Ṣe Wá Láǹfààní

Máa kíyè sí àwọn ohun tí Ọlọ́run dá (Job 12:​7-9; w09 4/15 6 ¶17)

Mú àwọn tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú wọn lọ́rẹ̀ẹ́ (Job 12:12; w21.06 10-11 ¶10-12)

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn ìlànà Ọlọ́run, kó o sì máa fi wọ́n sílò nígbèésí ayé rẹ (Job 12:16; it-2 1190 ¶2)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Bí mo ṣe ń wà pẹ̀lú àwọn Kristẹni tí òtítọ́ jinlẹ̀ nínú wọn, kí ni mo ti rí kọ́ lára wọn?’