Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́

Ìbéèrè: Kí ni Ìjọba Ọlọ́run?

Bíbélì: Ais 9:​6, 7 tàbí Mt 6:​9, 10

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ni Ìjọba Ọlọ́run máa ṣe?

WÀÁ RÍ ẸSẸ BÍBÉLÌ YÌÍ NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́:

ÌPADÀBẸ̀WÒ

Ìbéèrè: Kí ni Ìjọba Ọlọ́run máa ṣe?

Bíbélì: Sm 72:16 tàbí Mt 14:​19, 20

Ìbéèrè fún ìgbà míì: Ìgbà wo ni Ìjọba Ọlọ́run máa ṣàkóso ayé?

WÀÁ RÍ SÁÀMÙ 72:16 NÍNÚ ÀPÓTÍ ÌKỌ́NILẸ́KỌ̀Ọ́: