Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Jèhófà Ni Bàbá Wa

Jèhófà Ni Bàbá Wa

Kí lò lè jẹ́ kó dá àwọn ọmọ rẹ lójú pé Jèhófà dà bí bàbá fún wa?

Ẹ̀yin òbí, ẹ ka Àìsáyà 64:8 kí ẹ sì jíròrò ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ yín.

Tẹ ẹ̀kọ́ yìí jáde.

Lẹ́yìn tí ẹ bá wo fídíò Jèhófà Ni Bàbá Wa ẹ jíròrò àwọn ìbéèrè tó wà ní ìsàlẹ̀. Àwọn ọmọ rẹ lè ya àwòrán tàbí kí wọ́n kọ àwọn nǹkan rere tí Jèhófà ti ṣe fún wọn.

O Tún Lè Wo

OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ

Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Eré

Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.