Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Máa Rántí Àwọn Tó Ń Ṣe Iṣẹ́ Ìsìn Alákòókò Kíkún

Máa Rántí Àwọn Tó Ń Ṣe Iṣẹ́ Ìsìn Alákòókò Kíkún

Àwọn nǹkan wo la lè ṣe láti fún Jèhófà ní ohun tó dára jù lọ? Ronú onírúurú nǹkan tó o lè ṣe láti ran àwọn tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún lọ́wọ́.

O Tún Lè Wo

OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ

Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Eré

Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.