Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI GAN-AN? (ÌWÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Àwọn Ẹ̀dá Ẹ̀mí​—Ohun Tí Wọ́n Ń Ṣe fún Wa (Apá 2)

Orí kẹwàá ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé

Kí nìdí tí Jèhófà fi pàṣẹ pé a ò gbọ́dọ̀ lọ́wọ́ sí ìbẹ́mìílò èyíkéyìí? Báwo la ṣe lè dáàbò bo ara wa lọ́wọ́ àwọn ẹ̀dá ẹ̀mí tí wọ́n fẹ́ ṣì wá lọ́nà?