Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ

Ádámù àti Éfà Mọ Tara Wọn Nìkan

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa Ádámù àti Éfà, tí wọ́n ṣe ìpinnu tí ò dáa torí pé wọ́n mọ tara wọn nìkan, tó sì wá kó bá gbogbo aráyé. Ka ọ̀rọ̀ inú àwòrán ìtàn Bíbélì yìí lórí ìkànnì wa tàbí kó o tẹ̀ ẹ́ jáde.