Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI GAN-AN? (ÌWÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Ìjọsìn Tó Ní Ìtẹ́wọ́gbà Ọlọ́run (Apá 2)

Orí kẹẹ̀ẹ́dógún ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Ṣé kéèyàn kàn gba Ọlọ́run gbọ́ nìkan tó? Àbí ohun tó ń béèrè lọ́wọ́ àwọn tó ń sìn ín jù bẹ́ẹ̀ lọ?