Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ

Jèhófà Máa Ń Dárí Jini Pátápátá

Ọba Mánásè ṣe àwọn ohun tó burú gan-an, àmọ́ Jèhófà dárí jì í. Kí nìdí? Ka àwòrán ìtàn Bíbélì yìí lórí ìkànnì wa tàbí kó o tẹ̀ ẹ́ jáde.