Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Sọ Òtítọ́ Di Tìẹ

Sọ Òtítọ́ Di Tìẹ

Tá a bá sọ òtítọ́ di tiwa, a máa di ọ̀rẹ́ Jèhófà. Jẹ́ ká wo bá a ṣe lè ṣe é.

O Tún Lè Wo

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Sọ Òtítọ́ Di Tìrẹ (Orin 64)

Ṣé o ti ṣe bẹ́ẹ̀?

OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ

Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Eré

Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.