Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ọlọ́run Dá Mi Lọ́nà Ìyanu

Ọlọ́run Dá Mi Lọ́nà Ìyanu

Ọ̀nà ìyanu ní Jèhófà dá wa! Jẹ́ ká wo ìdí tá a fi sọ bẹ́ẹ̀.

O Tún Lè Wo

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Ọlọ́run Dá Mi Lọ́nà Ìyanu

Torí pé Ọlọ́run Ọlọ́run dá ẹ lọ́nà ìyanu, o lè gbọ́ràn, o lè rẹ́rìn-ín, o sì lè ṣeré.

OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ

Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Eré

Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.

Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.