ILÉ ÌṢỌ́ August 2010 Kí Ló Ń Ba Ọ̀pọ̀ Èèyàn Lẹ́rù? Ìdáhùn sí Ìbéèrè Mẹ́rin Nípa Òpin Ayé Wọn Kò Bẹ̀rù Òpin Ayé Mọ́ OHUN TÓ LÈ MÚ KÍ ÌDÍLÉ LÁYỌ̀ Bí O Ṣe Lè Ṣàṣeyọrí Nínú Ọdún Àkọ́kọ́ Ìgbéyàwó KỌ ỌMỌ RẸ Kí Nìdí Tí Jésù Kò Fi Kánjú Bí A Ṣe Lè Láyọ̀ Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà ÀWỌN ÒǸKÀWÉ WA BÉÈRÈ PÉ Ǹjẹ́ Gbogbo Èèyàn Ló Láǹfààní Kan Náà Láti Mọ Ọlọ́run? Ǹjẹ́ O Mọ̀? “Káfíńtà” “Gbé Ọmọkùnrin Rẹ” A Rán Àwọn Míṣọ́nnárì Jáde Láti Sọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn