ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ March 2015

Awon apileko ta a maa kekoo lati May 4 si 31, 2015 lo wa ninu eda yii.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

A Ri Ohun To San Ju Ta A Fi Igbesi Aye Wa Se

David ati Gwen Cartwright ti figba kan jo ijo alalooyipo pa po, amo ni bayii won ti wa n jumo lo ese won fun ohun to san ju.

Eyi Ni “Ona Ti Iwo Tewo Gba”

Ki nidi ti awon iwe wa lawon odun aipe yii fi saba maa n salaye awon akosile Bibeli lona to tubo rorun, to si se kedere?

Se Waa “Maa Ba A Niso Ni Sisona”?

Ka oye to se kedere nipa akawe ti Jesu se nipa awon wundia mewaa naa, eyi to da lori eko to rorun lati loye to si je kanjukanju to wa ninu akawe naa.

Ibeere Lati Owo Awon Onkawe

Nigba kan, awon itejade wa maa n soro nipa awon eni kan, isele kan tabi ohun kan ninu Bibeli to n sapeere nnkan mii to maa waye lojo iwaju, amo lawon odun aipe yii a ki i saba se bee. Ki nidi?

Kekoo Latinu Apejuwe Nipa Talenti

Apileko yii tun oye wa se nipa akawe nipa talenti.

Maa Fi Idurosinsin Ti Awon Arakunrin Kristi Leyin

Bawo lawon ti Kristi maa sedajo won gege bi aguntan se n ti awon arakunrin re leyin?

Gbeyawo “Kiki Ninu Oluwa”—Nje O Si Bogbon Mu?

Awon to ba pinnu lati te le imoran Olorun maa n munu Olorun dun, won si maa n ni opo ibukun temi.