Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ILÉ ÌṢỌ́ No. 2 2018 | Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Iwájú?

KÍ LÓ MÁA ṢẸLẸ̀ LỌ́JỌ́ IWÁJÚ?

Ṣé o máa ń ronú nípa bí ọjọ́ ọ̀la ìwọ àti ìdílé rẹ ṣe máa rí? Bíbélì sọ pé:

“Àwọn olódodo ni yóò ni ilẹ̀ ayé, wọn yóò sì máa gbé títí láé lórí rẹ̀.”​—Sáàmù 37:29.

Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ yìí máa jẹ́ kó o mọ àwọn ohun àgbàyanu tí Ọlọ́run fẹ́ ṣe fún ilẹ̀ ayé àti àwa èèyàn, á tún jẹ́ kó o mọ ohun tó yẹ kó o ṣe láti jàǹfààní nínú rẹ̀.

 

Ohun Táwọn Kan Sọ Nípa Ọjọ́ Iwájú

Àwọn èèyàn ti sọ oríṣiríṣi nǹkan nípa ọjọ́ iwáú. Àwọn ohun kan tí wọn sọ ṣẹlẹ̀, àmọ́ àwọn mí ì kò rí bí wọ́n ṣe sọ.

Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Tó Ti Ṣẹ

Àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì ti ṣẹ láìkù síbì kan.

Ohun Kan Tó Jẹ́ Ẹ̀rí Pé Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì Péye

Ohun ìṣẹ̀ǹbáyé kan ní Róòmù tó jẹ́ ẹ̀rí pé àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì péye.

Àwọn Ìlérí Tó Máa Ṣẹ

Ọ̀pọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì ló ti ṣẹ, àmọ́ ọjọ́ iwájú làwọn mí ì máa ṣẹ.

O Lè Wà Láàyè Títí Láé Lórí Ilẹ̀ Ayé

Bíbélì ṣàlàyé ohun tí Ọlọ́run fẹ́ ṣe fún aráyé.

Ìwọ Lo Máa Pinnu Bí Ọjọ́ Ọ̀la Rẹ Ṣe Máa Rí!

Àwọn kan gbà pé àyànmọ́ tàbí kádàrá ló ń darí ayé wọn. Ṣé bẹ́ẹ̀ lọ̀rọ̀ rí?

“Àwọn Ọlọ́kàn Tútù Ni Yóò Ni Ilẹ̀ Ayé”

Bíbélì ṣèlérí pé ìgbà kan ń bọ̀ tí ìwà ìrẹ́jẹ àti ìwà ìkà kò ní sí mọ́.