ILÉ ÌṢỌ́ No. 1 2019 | Ta Ni Ọlọ́run?

Gbé àwọn ìbéèrè mẹ́fà yẹ̀ wò tó máa jẹ́ kó o túbọ̀ sún mọ́ Ọlọ́run.

Ta Ni Ọlọ́run?

Kéèyàn tó lè sún mọ́ Ọlọ́run, á kọ́kọ́ mọ̀ ọ́n. Báwo lo ṣe lè ṣe bẹ́ẹ̀?

Kí Ni Orúkọ Ọlọ́run?

Ṣé o mọ̀ pé Ọlọ́run ní orúkọ kan tó jẹ́ kó yàtọ̀ gedegbe?

Irú Ẹni Wo Ni Ọlọ́run?

Kí ni àwọn ànímọ́ Ọlọ́run tó ta yọ jù?

Àwọn Nǹkan Wo Ni Ọlọ́run Ti Ṣe?

Ẹnu máa yà ẹ́ láti mọ̀ pé ọ̀pọ̀ nǹkan ni Ọlọ́run ti ṣe tá a ń jàǹfààní ẹ̀ títí dòní, tó sì máa ṣe wá láǹfààní lọ́jọ́ iwájú.

Àwọn Nǹkan Wo Ni Ọlọ́run Máa Ṣe?

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bí nǹkan ṣe máa rí tí Ìjọba Ọlọ́run bá bẹ̀rẹ̀ sí í ṣàkóso lórí ayé.

Àǹfààní Wo Lo Máa Rí Tó O Bá Mọ Ọlọ́run?

Àwọn ìbùkún wo ni a máa rí tá a bá sún mọ́ Ọlọ́run?

O Lè Sún Mọ́ Ọlọ́run

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ohun mẹ́rin tó o lè ṣe tó máa jẹ́ kó o sún mọ́ Ọlọ́run.