ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ March 2019

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti May 6 sí June 2, 2019 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí

Kí Ló Ń Dá Mi Dúró Láti Ṣèrìbọmi?

Àwọn kan wà tó ti mọ Jèhófà síbẹ̀ tí wọ́n ń fà sẹ́yìn láti ṣèrìbọmi. Kí ni irú àwọn bẹ́ẹ̀ lè ṣe láti borí àwọn ìṣòro wọn?

Fetí sí Ohùn Jèhófà

Àwọn ọ̀nà wo ni Jèhófà ń gbà bá wa sọ̀rọ̀ lónìí? Àǹfààní wo la máa rí tá a bá ń tẹ́tí sí i?

Máa Gba Tàwọn Míì Rò

Báwo ni Jèhófà àti Jésù ṣe fi hàn pé àwọn máa ń gba tàwọn míì rò, báwo la sì ṣe lè fara wé wọn?

Máa Gba Tàwọn Èèyàn Rò Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù

Àwọn nǹkan mẹ́rin wo la lè ṣe táá fi hàn pé a gba tàwọn tá à ń wàásù fún rò?

Ìwà Rere—Báwo Lo Ṣe Lè Ní In?

Kí ni ìwà rere? Kí nìdí tó fi yẹ ká sapá láti ní ànímọ́ yìí?

“Àmín” Wa Ṣe Pàtàkì sí Jèhófà

Ọ̀pọ̀ èèyàn sábà máa ń ṣàmín lẹ́yìn àdúrà. Kí ni ọ̀rọ̀ yìí túmọ̀ sí, báwo sì ni wọ́n ṣe lò ó nínú Bíbélì?