JÍ! No. 1 2020 | Bó O Ṣe Lè Ní Ìbàlẹ̀ Ọkàn

Àìbalẹ̀ ọkàn ń pọ̀ sí i. Àmọ́ ọ̀pọ̀ nǹkan wà tó o lè ṣe láti ní ìbàlẹ̀ ọkàn.

Kí Ló Ń Kó Ẹ Lọ́kàn Sókè?

Ọ̀pọ̀ nǹkan lo lè ṣe kí àìbalẹ̀ ọkàn má bàa ṣàkóbá fún ẹ.

Kí Ló Ń Fa Àìbalẹ̀ Ọkàn?

Wo àwọn ohun tó ń fa àìbalẹ̀ ọkàn kó o sì wo èyí tó kàn ẹ́ lára wọn.

Kí Ni Àìbalẹ̀ Ọkàn?

Àìbalẹ̀ ọkàn ti di apá kan ìgbésí ayé àwa èèyàn. Wo bí àpọ̀jù rẹ̀ ṣe lè ṣàkóbá fún ara rẹ.

Bó O Ṣe Lè Kojú Àìbalẹ̀ Ọkàn

Wo àwọn ìlànà mélòó kan tó lè jẹ́ kó o kojú àìbalẹ̀ ọkàn tàbí kó o dín in kù.

Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Tí Ọkàn Gbogbo Èèyàn Máa Balẹ̀

A ò lágbára láti yanjú gbogbo ohun tó ń fa àìbalẹ̀ ọkàn. Àmọ́ Jèhófà lè yanjú ẹ̀.

“Ìbàlẹ̀ Ọkàn Ń Mú Kí Ara Lókun”

Ọ̀rọ̀ tó wà ní Òwe 14:30 jẹ́ ara ọ̀rọ̀ ọgbọ́n tó wúlò nígbà gbogbo tó wà nínú Bíbélì.