ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ February 2021 Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti April 5–May 2, 2021 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí. “Orí Gbogbo Ọkùnrin Ni Kristi” “Orí Obìnrin Ni Ọkùnrin” Mọyì Ipò Orí Tí Jèhófà Ṣètò Nínú Ìjọ ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ Jèhófà ‘Mú Kí Àwọn Ọ̀nà Mi Tọ́’ Arábìnrin Kan Rẹ́rìn-ín Músẹ́! Bá A Ṣe Lè Máa Láyọ̀ Tá A Bá Ń Fara Da Ìṣòro