ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ March 2021 Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti May 3–June 6, 2021 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí. Ẹ̀yin Ọ̀dọ́kùnrin, Ẹ Ṣe Ohun Tó Máa Jẹ́ Káwọn Míì Fọkàn Tán Yín Bí Gbogbo Ìjọ Ṣe Lè Mú Kí Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Kan Tẹ̀ Síwájú Kó sì Ṣèrìbọmi Bí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ṣe Lè Mú Kó O Fara Da Ìṣòro Ìfẹ́ Ń Jẹ́ Ká Lè Fara Da Ìkórìíra Jèhófà Máa Dáàbò Bò Ẹ́—Lọ́nà Wo? Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé