ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ February 2022

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti April 4–May 1, 2022 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 7

‘Fetí Sí Ọ̀rọ̀ Ọlọgbọ́n’

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 9

Máa Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Bíi Ti Jésù

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Mo Rí Ohun Tó Dáa Ju Iṣẹ́ Dókítà Lọ

Ìtàn ìgbésí ayé: René Ruhlmann

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Kí nìdí táwọn ọmọ Ísírẹ́lì àtijọ́ fi máa ń san owó orí ìyàwó?

Ǹjẹ́ O Mọ̀?

Kí nìdí tí Jèhófà fi gbà káwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa fi ẹyẹ oriri àti ẹyẹlé rúbọ?