ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ August 2023

Àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ ní October 9–November 5, 2023 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 33

Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Dáníẹ́lì

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní October 9-15, 2023

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 34

Ohun Tá A Rí Kọ́ Nínú Àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní October 16-22, 2023.

Tí Ọkọ Tàbí Aya Kan Bá Ń Wo Àwòrán Ìṣekúṣe

Báwo ni tọkọtaya ṣe lè ṣiṣẹ́ pa pọ̀ kí ọkọ lè jáwọ́ nínú wíwo àwòrán ìṣekúṣe tó ti mọ́ ọn lára, kí wọ́n lè pa dà fọkàn tán ara wọn?

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 35

Ẹ Máa Ní Sùúrù

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní October 23-29, 2023.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 36

Gbé Ẹrù Tó Yẹ Kó O Gbé, Kó O sì Ju Èyí Tí Ò Yẹ Nù

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní October 30–November 5, 2023.