ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ October 2023

Àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ ní December 11, 2023–January 7, 2024 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

1923—Ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Sẹ́yìn

Ọdún 1923 fún àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì níṣìírí torí pé bí wọ́n ṣe ń jọ́sìn, tí wọ́n sì ń wàásù jẹ́ kí wọ́n wà níṣọ̀kan, ìyẹn sì fi hàn pé ìjọsìn tòótọ́ là ń ṣe.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 42

Ṣé O “Ṣe Tán Láti Ṣègbọràn”?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní December 11-17, 2023.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 43

‘Jèhófà Máa Sọ Ẹ́ Di Alágbára’

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní December 18-24, 2023.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 44

Máa Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Jinlẹ̀

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní December 25-31, 2023.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 45

Mọyì Àǹfààní Tó O Ní Láti Jọ́sìn Jèhófà Nínú Tẹ́ńpìlì Tẹ̀mí

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní January 1-7, 2024.

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Ṣé mánà àti àparò nìkan làwọn ọmọ Ísírẹ́lì jẹ nígbà tí wọ́n wà ní aginjù?