Tí Ẹni Tó O Fẹ́ràn Bá Kú TẸ̀ Ẹ̣́ Tí Ẹni Tó O Fẹ́ràn Bá Kú Àwọn nǹkan kan wà tó o lè ṣe tó máa mú kára tù ẹ́ tó o bá ń ṣọ̀fọ̀. Máà bínú, ètò tó o fi ń wo fídíò kò ṣiṣẹ́. Wa Fídíò Yìí Jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Bó O Ṣe Lè Fara Da Àjálù O Tún Lè Wo JÍ! Ohun Tó Lè Ran Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Lọ́wọ́ Ọ̀pọ̀ èèyàn tó ń ṣọ̀fọ̀ ló ti rí ìrànlọ́wọ́ gbà torí pé wọ́n ṣe àwọn nǹkan tó yẹ. ÀKÓJỌ ÀPILẸ̀KỌ ÀTI FÍDÍÒ Bá A Ṣe Lè Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú Téèyàn wa bá kú, ó lè máa ṣe wá bíi pé kò sẹ́ni tó mọ bó ṣe rí lára wa. Àmọ́ Ọlọ́run mọ̀ ọ́n, ó sì fẹ́ tù wá nínú. ILÉ ÌṢỌ́ Tí Ẹnì Kan Tó O Fẹ́ràn Bá Kú, Ṣé Ayé Rẹ Ṣì Lè Dùn? Wo ohun márùn-ún tó o lè ṣe tí ẹnì kan tó o fẹ́ràn bá kú. Nígbà Tí Ẹnìkan Tí Ìwọ Fẹ́ràn Bá Kú Báwo Ni Mo Ṣe Lè Gbé Pẹ̀lú Ẹ̀dùn-Ọkàn Mi? Ṣé ó yẹ kó o fi bí ọ̀rọ̀ ṣe rí lára rẹ̀ hàn àbí kó o bò ó mọ́ra? ILÉ ÌṢỌ́ Ó Ń Jẹ́ Ká Fara Da Ìṣòro Àwọn ìṣòro kan wà tá ò lè yẹra fún, kò sì sí ohun tá a lè ṣe láti yanjú wọn báyìí, irú bí ikú èèyàn wa kan tàbí àìsàn tó le gan-an. ILÉ ÌṢỌ́ Bá A Ṣe Lè Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú Àwọn ọ̀rẹ́ tó sún mọ́ra pàápàá lè má mọ ohun tí ọ̀rẹ́ wọn tí ọ̀fọ̀ ṣẹ̀ nílò. Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Tí Ẹni Tó O Fẹ́ràn Bá Kú ÀKÓJỌ ÀPILẸ̀KỌ ÀTI FÍDÍÒ Tí Ẹni Tó O Fẹ́ràn Bá Kú Yorùbá Tí Ẹni Tó O Fẹ́ràn Bá Kú https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/501100015/univ/art/501100015_univ_sqr_xl.jpg mrt àpilẹ̀kọ 31