ÀWỌN ERÉ OJÚ PÁTÁKÓ Máa Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò TẸ̀ Ẹ̣́ Máa Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò Kọ́ nípa bí o ṣe lè ṣọ́ra fún àwọn ewu tó wà nínú lílo ìkànnì àjọlò. Máà bínú, ètò tó o fi ń wo fídíò kò ṣiṣẹ́. Wa Fídíò Yìí Jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Àjọṣe Rẹ Pẹ̀lú Àwọn Míì Àlàáfíà àti Ayọ̀ Àwọn Eré Ojú Pátákó Ọ̀dọ́ O Tún Lè Wo ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Àkóbá Wo Ni Ìkànnì Àjọlò Lè Ṣe fún Mi? Lílo ìkànnì àjọlò lè di bárakú. Àwọn àbá yìí lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó má bàa kó bá ẹ. ÌGBÉYÀWÓ ÀTI ÌDÍLÉ Kọ́ Ọmọ Rẹ Láti Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò Ran ọmọ rẹ lọ́wọ́ kó má bàa kó sínú ewu ìkànnì àjọlò. ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Fífọ̀rọ̀ Ránṣẹ́ Lórí Fóònù? Ọ̀rọ tó o fi ránṣẹ́ lórí fóònù lè ba àjọṣe tó o ní pẹ̀lú àwọn míì jẹ́, ó sì lè bà ẹ́ lórúkọ̀ jẹ́. Kà bó ṣe lè ṣẹlẹ̀. ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Fífi Ohun Tó Ń Mọ́kàn Fà sí Ìṣekúṣe Ránṣẹ́ Lórí Fóònù? Ṣé àwọn ọ̀rẹ́ rẹ ò tíì máa fipá mú ẹ pé kó o fi ohun tó ń mọ́kàn fà sí ìṣekúṣe ránṣẹ́ sáwọn lórí fóònù? Kí ló lè tẹ̀yìn ẹ̀ yọ tó o bá ṣe bẹ́ẹ̀? Àbí o rò pé kò sóhun tó burú níbẹ̀, pé ẹ kàn ń tage lásán ni? Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Máa Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò ÀWỌN ERÉ OJÚ PÁTÁKÓ Máa Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò Yorùbá Máa Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502014276/univ/art/502014276_univ_sqr_xl.jpg