Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wá Àwọn Ọ̀rẹ́ ní Ibi tí O Ò Lérò

Wá Àwọn Ọ̀rẹ́ ní Ibi tí O Ò Lérò

Ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Akil nínú fídíò yìí ni pé ó ti kó kúrò níbi táwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ wà. Àmọ́ ìtàn Dáfídì àti Jónátánì ràn án lọ́wọ́ kó lè rí ọ̀rẹ́ níbi tí kò lérò.