Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Dáfídì—Ó Gbẹ́kẹ̀ Lé Ọlọ́run

Dáfídì gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run. Kódà, nígbà tó dà bíi pé ìṣòro bò ó mọ́lẹ̀, kò fìgbà kan ṣíwọ́ pé òun ò sin Ọlọ́run mọ́. Wo bí Jèhófà ṣe bù kún Dáfídì torí pé ó jẹ́ adúróṣinṣin, kó o sì wo bó ṣe máa bù kún àwa náà tá a bá tẹ̀ lé àpẹẹrẹ rere Dáfídì.

O Tún Lè Wo

KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ

Káàdì Eré Bíbélì Nípa Dáfídì

Ó ṣeé ṣe kó o mọ ìtàn Dáfídì àti Gòláyátì, àmọ́ ọ̀pọ̀ nǹkan ló ṣì yẹ kó o mọ̀ nípa Dáfídì.

ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ

Dáfídì Jẹ́ Onígboyà

Kí ló mú kí Dáfídì gbà pá òun lè ṣẹ́gun Gòláyátì? Kí ló sì lè mú kó o nígboyà láti ṣe ohun tó tọ́?

ERÉ ALÁWÒRÁN

Dáfídì Wá ní Orúkọ Ọlọ́run

Kọ́ ọmọ rẹ ní ìtumọ̀ orúkọ Ọlọ́run.

ERÉ ALÁWÒRÁN

Dáfídì Nígboyà, Bí Ò Tiẹ̀ Ní Ju Ohun Ìjà Díẹ̀

Mú káàdì tí wọ́n ya àwọn èèyàn inú Bíbélì sí tó bára mu pẹ̀lú èyí tí wọ́n ya àwòrán àwọn nǹkan míì sí.