YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 Ìwé Ẹ́sírà Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ọba Kírúsì pàṣẹ pé kí wọ́n tún tẹ́ńpìlì kọ́ (1-4) Ètò tí wọ́n ṣe kí àwọn tó wà nígbèkùn ní Bábílónì lè pa dà (5-11) 2 Orúkọ àwọn tó pa dà láti ìgbèkùn (1-67) Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì (43-54) Àwọn ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì (55-57) Àwọn ọrẹ àtinúwá fún tẹ́ńpìlì (68-70) 3 Wọ́n tún pẹpẹ kọ́, wọ́n sì rú àwọn ẹbọ (1-6) Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í tún tẹ́ńpìlì kọ́ (7-9) Wọ́n fi ìpìlẹ̀ tẹ́ńpìlì lélẹ̀ (10-13) 4 Wọ́n gbógun ti iṣẹ́ títún tẹ́ńpìlì kọ́ (1-6) Àwọn ọ̀tá fi ìwé ẹ̀sùn ránṣẹ́ sí Ọba Atasásítà (7-16) Ìdáhùn Atasásítà (17-22) Iṣẹ́ kíkọ́ tẹ́ńpìlì dáwọ́ dúró (23-24) 5 Àwọn Júù pa dà sẹ́nu kíkọ́ tẹ́ńpìlì (1-5) Lẹ́tà tí Táténáì kọ sí Ọba Dáríúsì (6-17) 6 Àyẹ̀wò tí Dáríúsì ṣe àti àṣẹ tó pa (1-12) Wọ́n parí tẹ́ńpìlì, wọ́n sì ṣe ayẹyẹ ìṣílé (13-18) Wọ́n ṣe Ìrékọjá (19-22) 7 Ẹ́sírà wá sí Jerúsálẹ́mù (1-10) Lẹ́tà tí Atasásítà kọ sí Ẹ́sírà (11-26) Ẹ́sírà yin Jèhófà (27-28) 8 Orúkọ àwọn tó tẹ̀ lé Ẹ́sírà pa dà (1-14) Wọ́n múra ìrìn àjò náà (15-30) Wọ́n kúrò ní Bábílónì, wọ́n dé sí Jerúsálẹ́mù (31-36) 9 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti àwọn ọmọ ilẹ̀ míì ń fẹ́ ara wọn (1-4) Àdúrà ìjẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ tí Ẹ́sírà gbà (5-15) 10 Wọ́n dá májẹ̀mú láti lé àwọn aya àjèjì lọ (1-14) Wọ́n lé àwọn aya àjèjì lọ (15-44) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Ẹ́sírà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Ẹ́sírà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Ẹ́sírà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Ẹ́sírà ojú ìwé 642