YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 Lẹ́tà sí Àwọn Ará Éfésù Orí 1 2 3 4 5 6 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ìkíni (1, 2) Àwọn ìbùkún tẹ̀mí (3-7) À ń kó ohun gbogbo jọ nínú Kristi (8-14) “Iṣẹ́ àbójútó kan” ní àwọn àkókò tí a ti yàn (10) A fi ẹ̀mí gbé èdìdì lé wọn gẹ́gẹ́ bí “àmì ìdánilójú” (13, 14) Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nítorí ìgbàgbọ́ àwọn ará Éfésù, ó sì gbàdúrà fún wọn (15-23) 2 Ọlọ́run sọ wọ́n di ààyè pẹ̀lú Kristi (1-10) A wó ògiri tó pààlà (11-22) 3 Àwọn Kèfèrí wọnú àṣírí mímọ́ (1-13) Àwọn Kèfèrí di ajùmọ̀jogún pẹ̀lú Kristi (6) Ìpinnu ayérayé Ọlọ́run (11) Àdúrà pé kí àwọn ará Éfésù ní òye (14-21) 4 Ìṣọ̀kan nínú ara Kristi (1-16) Àwọn ẹ̀bùn tí ó jẹ́ èèyàn (8) Ìwà àtijọ́ àti ìwà tuntun (17-32) 5 Ọ̀rọ̀ mímọ́ àti ìwà mímọ́ (1-5) Ẹ máa rìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìmọ́lẹ̀ (6-14) Ẹ máa kún fún ẹ̀mí (15-20) Ẹ máa lo àkókò yín lọ́nà to dára jù lọ (16) Ìmọ̀ràn fún àwọn ọkọ àti ìyàwó (21-33) 6 Ìmọ̀ràn fún àwọn ọmọ àti òbí (1-4) Ìmọ̀ràn fún àwọn ẹrú àti ọ̀gá (5-9) Gbogbo ìhámọ́ra ogun láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run (10-20) Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (21-24) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Éfésù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Éfésù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Éfésù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Éfésù ojú ìwé 1558