YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 17 18 19 20 21 22 23 24 25 26 27 28 Ìṣe Àwọn Àpọ́sítélì Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 17 18 19 20 21 22 23 24 25 26 27 28 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ó kọ̀wé sí Tìófílọ́sì (1-5) Iṣẹ́ ìwàásù máa dé gbogbo ìkángun ayé (6-8) Jésù gòkè lọ sọ́run (9-11) Àwọn ọmọ ẹ̀yìn kóra jọ ní ìṣọ̀kan (12-14) Wọ́n yan Màtáyásì rọ́pò Júdásì (15-26) 2 Ẹ̀mí mímọ́ tú jáde ní Pẹ́ńtíkọ́sì (1-13) Ọ̀rọ̀ Pétérù (14-36) Ọ̀pọ̀ èèyàn gba ọ̀rọ̀ tí Pétérù sọ (37-41) Èèyàn 3,000 ṣèrìbọmi (41) Ìbákẹ́gbẹ́ Kristẹni (42-47) 3 Pétérù wo arọ tó ń tọrọ nǹkan sàn (1-10) Ọ̀rọ̀ tí Pétérù sọ ní Ọ̀dẹ̀dẹ̀ Sólómọ́nì (11-26) ‘Ìmúbọ̀sípò ohun gbogbo’ (21) Wòlíì kan bíi Mósè (22) 4 Wọ́n mú Pétérù àti Jòhánù (1-4) Iye àwọn onígbàgbọ́ di 5,000 ọkùnrin (4) Ìgbẹ́jọ́ níwájú Sàhẹ́ndìrìn (5-22) ‘A ò lè ṣàì sọ̀rọ̀’ (20) Àdúrà ìgboyà (23-31) Àwọn ọmọ ẹ̀yìn jọ pín ohun tí wọ́n ní (32-37) 5 Ananáyà àti Sàfírà (1-11) Àwọn àpọ́sítélì ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì (12-16) Wọ́n fi wọ́n sẹ́wọ̀n, wọ́n sì dá wọn sílẹ̀ (17-21a) Wọ́n tún mú wọn wá síwájú Sàhẹ́ndìrìn (21b-32) ‘Ṣègbọràn sí Ọlọ́run dípò èèyàn’ (29) Ìmọ̀ràn Gàmálíẹ́lì (33-40) Wọ́n ń wàásù láti ilé dé ilé (41, 42) 6 Wọ́n yan ọkùnrin méje láti máa ṣe iṣẹ́ ìránṣẹ́ (1-7) Wọ́n fẹ̀sùn kan Sítéfánù pé ó sọ̀rọ̀ òdì (8-15) 7 Ọ̀rọ̀ tí Sítéfánù sọ níwájú Sàhẹ́ndìrìn (1-53) Ìgbà ayé àwọn baba ńlá (2-16) Mósè ṣe aṣáájú; Ísírẹ́lì bọ̀rìṣà (17-43) Ọlọ́run kì í gbé inú tẹ́ńpìlì tí èèyàn kọ́ (44-50) Wọ́n sọ Sítéfánù lókùúta (54-60) 8 Sọ́ọ̀lù ṣe inúnibíni (1-3) Ìwàásù Fílípì sèso rere ní Samáríà (4-13) Wọ́n rán Pétérù àti Jòhánù lọ sí Samáríà (14-17) Símónì fẹ́ ra ẹ̀mí mímọ́ (18-25) Ìwẹ̀fà ará Etiópíà (26-40) 9 Sọ́ọ̀lù wà ní ọ̀nà Damásíkù (1-9) Olúwa rán Ananáyà pé kó lọ ran Sọ́ọ̀lù lọ́wọ́ (10-19a) Sọ́ọ̀lù wàásù nípa Jésù ní Damásíkù (19b-25) Sọ́ọ̀lù wá sí Jerúsálẹ́mù (26-31) Pétérù wo Énéà sàn (32-35) Dọ́káàsì tó jẹ́ ọ̀làwọ́ jíǹde (36-43) 10 Ìran tí Kọ̀nílíù rí (1-8) Pétérù rí àwọn ẹranko tí a ti sọ di mímọ́ nínú ìran (9-16) Pétérù wá sílé Kọ̀nílíù (17-33) Pétérù kéde ìhìn rere fún àwọn Kèfèrí (34-43) “Ọlọ́run kì í ṣe ojúsàájú” (34, 35) Àwọn Kèfèrí gba ẹ̀mí mímọ́, wọ́n sì ṣèrìbọmi (44-48) 11 Pétérù ròyìn fún àwọn àpọ́sítélì (1-18) Bánábà àti Sọ́ọ̀lù wà ní Áńtíókù ti Síríà (19-26) Ìgbà àkọ́kọ́ tí a pe àwọn ọmọ ẹ̀yìn ní Kristẹni (26) Ágábù sọ tẹ́lẹ̀ pé ìyàn máa mú (27-30) 12 Wọ́n pa Jémíìsì; wọ́n fi Pétérù sẹ́wọ̀n (1-5) Ọlọ́run dá Pétérù sílẹ̀ lọ́nà ìyanu (6-19) Áńgẹ́lì kọ lu Hẹ́rọ́dù (20-25) 13 Wọ́n rán Bánábà àti Sọ́ọ̀lù láti lọ ṣe míṣọ́nnárì (1-3) Iṣẹ́ ìwàásù ní Sápírọ́sì (4-12) Ọ̀rọ̀ tí Pọ́ọ̀lù sọ ní Áńtíókù ti Písídíà (13-41) Àsọtẹ́lẹ̀ tó fún wọn láṣẹ láti yíjú sí àwọn orílẹ̀-èdè (42-52) 14 Ní Íkóníónì, àwọn ọmọ ẹ̀yìn ń pọ̀ sí i, inúnibíni sì ń ṣẹlẹ̀ (1-7) Ní Lísírà, wọ́n rò pé ọlọ́run ni wọ́n (8-18) Wọ́n sọ Pọ́ọ̀lù lókùúta, àmọ́ kò kú (19, 20) Wọ́n ń fún àwọn ìjọ lókun (21-23) Wọ́n pa dà sí Áńtíókù ti Síríà (24-28) 15 Awuyewuye ní Áńtíókù lórí ọ̀rọ̀ ìdádọ̀dọ́ (1, 2) Wọ́n gbé ọ̀rọ̀ náà lọ sí Jerúsálẹ́mù (3-5) Àwọn alàgbà àti àwọn àpọ́sítélì ṣèpàdé (6-21) Lẹ́tà látọ̀dọ̀ ìgbìmọ̀ olùdarí (22-29) Ta kété sí ẹ̀jẹ̀ (28, 29) Lẹ́tà náà gbé àwọn ìjọ ró (30-35) Pọ́ọ̀lù àti Bánábà lọ ní ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ (36-41) 16 Pọ́ọ̀lù mú Tímótì (1-5) Ìran ọkùnrin ará Makedóníà (6-10) Lìdíà di onígbàgbọ́ ní ìlú Fílípì (11-15) Wọ́n ju Pọ́ọ̀lù àti Sílà sẹ́wọ̀n (16-24) Ẹni tó ń ṣọ́ àwọn ẹlẹ́wọ̀n àti agbo ilé rẹ̀ ṣèrìbọmi (25-34) Pọ́ọ̀lù ní kí àwọn aláṣẹ wá tọrọ àforíjì (35-40) 17 Pọ́ọ̀lù àti Sílà ní Tẹsalóníkà (1-9) Pọ́ọ̀lù àti Sílà ní Bèróà (10-15) Pọ́ọ̀lù ní Áténì (16-22a) Ọ̀rọ̀ Pọ́ọ̀lù ní Áréópágù (22b-34) 18 Iṣẹ́ ìwàásù Pọ́ọ̀lù ní Kọ́ríńtì (1-17) Ó pa dà sí Áńtíókù ti Síríà (18-22) Pọ́ọ̀lù lọ sí Gálátíà àti Fíríjíà (23) Àpólò tó jẹ́ sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ rí ìrànlọ́wọ́ gbà (24-28) 19 Pọ́ọ̀lù ní Éfésù; àwọn kan tún batisí ṣe (1-7) Àwọn ohun tí Pọ́ọ̀lù ṣe láti kọ́ni (8-10) Ó ń ṣàṣeyọrí láìka àwọn tó ní ẹ̀mí èṣù sí (11-20) Éfésù dà rú (21-41) 20 Pọ́ọ̀lù ní Makedóníà àti ilẹ̀ Gíríìsì (1-6) Yútíkọ́sì jíǹde ní Tíróásì (7-12) Láti Tíróásì sí Mílétù (13-16) Pọ́ọ̀lù bá àwọn alàgbà Éfésù ṣèpàdé (17-38) Ó ń kọ́ni láti ilé dé ilé (20) “Ayọ̀ púpọ̀ wà nínú fífúnni” (35) 21 Lójú ọ̀nà Jerúsálẹ́mù (1-14) Wọ́n dé Jerúsálẹ́mù (15-19) Pọ́ọ̀lù tẹ̀ lé ìmọ̀ràn àwọn alàgbà (20-26) Inú tẹ́ńpìlì dà rú; wọ́n mú Pọ́ọ̀lù (27-36) Wọ́n gba Pọ́ọ̀lù láyè kó bá ọ̀pọ̀ èèyàn sọ̀rọ̀ (37-40) 22 Pọ́ọ̀lù gbèjà ara rẹ̀ níwájú ọ̀pọ̀ èèyàn (1-21) Pọ́ọ̀lù lo ẹ̀tọ́ ọmọ ìbílẹ̀ Róòmù tó ní (22-29) Sàhẹ́ndìrìn pé jọ (30) 23 Pọ́ọ̀lù sọ̀rọ̀ níwájú Sàhẹ́ndìrìn (1-10) Olúwa fún Pọ́ọ̀lù lókun (11) Wọ́n gbìmọ̀ pọ̀ láti pa Pọ́ọ̀lù (12-22) Wọ́n gbé Pọ́ọ̀lù lọ sí Kesaríà (23-35) 24 Wọ́n fẹ̀sùn kan Pọ́ọ̀lù (1-9) Pọ́ọ̀lù gbèjà ara rẹ̀ níwájú Fẹ́líìsì (10-21) Wọ́n dá ẹjọ́ Pọ́ọ̀lù dúró fún ọdún méjì (22-27) 25 Pọ́ọ̀lù jẹ́jọ́ níwájú Fẹ́sítọ́ọ̀sì (1-12) “Mo ké gbàjarè sí Késárì!” (11) Fẹ́sítọ́ọ̀sì fọ̀rọ̀ lọ Ọba Ágírípà (13-22) Pọ́ọ̀lù dúró níwájú Ágírípà (23-27) 26 Pọ́ọ̀lù gbèjà ara rẹ̀ níwájú Ágírípà (1-11) Pọ́ọ̀lù ṣàlàyé bó ṣe yí pa dà (12-23) Èsì Fẹ́sítọ́ọ̀sì àti ti Ágírípà (24-32) 27 Pọ́ọ̀lù wọkọ̀ òkun lọ sí Róòmù (1-12) Ìjì kọ lu ọkọ̀ òkun (13-38) Ọkọ̀ òkun fọ́ (39-44) 28 Wọ́n gúnlẹ̀ sí Málítà (1-6) Bàbá Púbílọ́sì rí ìwòsàn (7-10) Wọ́n forí lé Róòmù (11-16) Pọ́ọ̀lù bá àwọn Júù sọ̀rọ̀ ní Róòmù (17-29) Pọ́ọ̀lù fi ìgboyà wàásù fún ọdún méjì (30, 31) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Ìṣe—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Ìṣe—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Ìṣe—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Ìṣe ojú ìwé 1453-1455