YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 17 18 19 20 21 22 23 24 25 26 27 28 29 Ìwé Kíróníkà Kìíní Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 17 18 19 20 21 22 23 24 25 26 27 28 29 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Látọ̀dọ̀ Ádámù dé ọ̀dọ̀ Ábúráhámù (1-27) Àwọn àtọmọdọ́mọ Ábúráhámù (28-37) Àwọn ọmọ Édómù àti àwọn ọba wọn pẹ̀lú àwọn Séríkí wọn (38-54) 2 Àwọn ọmọ 12 tí Ísírẹ́lì bí (1, 2) Àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà (3-55) 3 Àwọn àtọmọdọ́mọ Dáfídì (1-9) Àwọn ọmọ tó wá láti ìdílé ọba Dáfídì (10-24) 4 Àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà tó ṣẹ́ kù (1-23) Jábésì àti àdúrà rẹ̀ (9, 10) Àwọn àtọmọdọ́mọ Síméónì (24-43) 5 Àwọn àtọmọdọ́mọ Rúbẹ́nì (1-10) Àwọn àtọmọdọ́mọ Gádì (11-17) Wọ́n ṣẹ́gun àwọn ọmọ Hágárì (18-22) Ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè (23-26) 6 Àwọn àtọmọdọ́mọ Léfì (1-30) Àwọn akọrin inú tẹ́ńpìlì (31-47) Àwọn àtọmọdọ́mọ Áárónì (48-53) Àwọn ibi tí àwọn ọmọ Léfì gbé (54-81) 7 Àwọn àtọmọdọ́mọ Ísákà (1-5), ti Bẹ́ńjámínì (6-12), ti Náfútálì (13), ti Mánásè (14-19), ti Éfúrémù (20-29) àti ti Áṣérì (30-40) 8 Àwọn àtọmọdọ́mọ Bẹ́ńjámínì (1-40) Ìlà ìdílé Sọ́ọ̀lù (33-40) 9 Àwọn orúkọ tó wà nínú àkọsílẹ̀ ìlà ìdílé lẹ́yìn tí wọ́n dé láti ìgbèkùn (1-34) A tún orúkọ àwọn tó wà nínú ìdílé Sọ́ọ̀lù kọ (35-44) 10 Ikú Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọmọ rẹ̀ (1-14) 11 Gbogbo Ísírẹ́lì fòróró yan Dáfídì ṣe ọba (1-3) Dáfídì gba Síónì (4-9) Àwọn jagunjagun Dáfídì tó lákíkanjú (10-47) 12 Àwọn tó ń ti ìjọba Dáfídì lẹ́yìn (1-40) 13 Wọ́n gbé Àpótí wá láti Kiriati-jéárímù (1-14) Ọlọ́run pa Úsà (9, 10) 14 Ọlọ́run fìdí ìjọba Dáfídì múlẹ̀ (1, 2) Ìdílé Dáfídì (3-7) Wọ́n ṣẹ́gun àwọn Filísínì (8-17) 15 Àwọn ọmọ Léfì gbé Àpótí lọ sí Jerúsálẹ́mù (1-29) Míkálì pẹ̀gàn Dáfídì (29) 16 Wọ́n gbé Àpótí náà sínú àgọ́ (1-6) Orin ìdúpẹ́ tí Dáfídì kọ (7-36) “Jèhófà ti di Ọba!” (31) Iṣẹ́ ìsìn níwájú Àpótí náà (37-43) 17 Dáfídì kò ní kọ́ tẹ́ńpìlì (1-6) Ọlọ́run bá Dáfídì dá májẹ̀mú ìjọba (7-15) Àdúrà ìdúpẹ́ tí Dáfídì gbà (16-27) 18 Àwọn tí Dáfídì ṣẹ́gun (1-13) Ìjọba Dáfídì (14-17) 19 Àwọn ọmọ Ámónì dójú ti àwọn òjíṣẹ́ Dáfídì (1-5) Wọ́n ṣẹ́gun Ámónì àti Síríà (6-19) 20 Wọ́n gba Rábà (1-3) Wọ́n pa àwọn òmìrán Filísínì (4-8) 21 Ìkànìyàn tí kò bófin mu tí Dáfídì ṣe (1-6) Ìyà tí Jèhófà fi jẹ wọ́n (7-17) Dáfídì mọ pẹpẹ (18-30) 22 Ètò tí Dáfídì ṣe sílẹ̀ fún kíkọ́ tẹ́ńpìlì (1-5) Dáfídì sọ ohun tí Sólómọ́nì máa ṣe fún un (6-16) Ó ní kí àwọn ìjòyè ran Sólómọ́nì lọ́wọ́ (17-19) 23 Dáfídì ṣètò àwọn ọmọ Léfì (1-32) A ya Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ sọ́tọ̀ (13) 24 Dáfídì ṣètò àwọn àlùfáà sí àwùjọ 24 (1-19) Àwọn iṣẹ́ míì tí a fún àwọn ọmọ Léfì (20-31) 25 Àwọn olórin àti àwọn akọrin ilé Ọlọ́run (1-31) 26 A pín àwọn aṣọ́bodè sí àwùjọ-àwùjọ (1-19) Àwọn olùtọ́jú ibi ìṣúra àti àwọn òṣìṣẹ́ míì (20-32) 27 Àwọn aláṣẹ nídìí iṣẹ́ ọba (1-34) 28 Ọ̀rọ̀ tí Dáfídì sọ lórí kíkọ́ tẹ́ńpìlì (1-8) Ó sọ ohun tí Sólómọ́nì máa ṣe; ó fún un ní àwòrán ìkọ́lé (9-21) 29 Ọrẹ fún tẹ́ńpìlì (1-9) Àdúrà Dáfídì (10-19) Inú àwọn èèyàn dùn; ìjọba Sólómọ́nì (20-25) Ikú Dáfídì (26-30) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ 1 Kíróníkà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) 1 Kíróníkà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá 1 Kíróníkà—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt 1 Kíróníkà ojú ìwé 554-555