YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 Lẹ́tà Kìíní Tí Pétérù Kọ Orí 1 2 3 4 5 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ìkíni (1, 2) Ìbí tuntun tó jẹ́ ká lè ní ìrètí tó wà láàyè (3-12) Ẹ jẹ́ mímọ́ bí ọmọ tó ń ṣègbọràn (13-25) 2 Kí ọ̀rọ̀ náà máa wù yín (1-3) Òkúta ààyè tí a fi kọ́ ilé tẹ̀mí (4-10) Ẹ máa gbé bí àjèjì nínú ayé (11, 12) Àwọn tó yẹ ká tẹrí ba fún (13-25) Kristi fi àpẹẹrẹ lélẹ̀ fún wa (21) 3 Àwọn ọkọ àti àwọn aya (1-7) Ẹ máa bára yín kẹ́dùn; ẹ máa wá àlàáfíà (8-12) Tí a bá ń jìyà nítorí òdodo (13-22) Ẹ ṣe tán láti gbèjà ìrètí yín (15) Ìrìbọmi àti ẹ̀rí ọkàn rere (21) 4 Ẹ ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run bíi ti Kristi (1-6) Òpin ohun gbogbo ti sún mọ́lé (7-11) Tí a bá ń jìyà torí pé a jẹ́ Kristẹni (12-19) 5 Ẹ máa ṣe olùṣọ́ àgùntàn agbo Ọlọ́run (1-4) Ẹ jẹ́ onírẹ̀lẹ̀, kí ẹ sì wà lójúfò (5-11) Ẹ máa kó gbogbo àníyàn yín lé Ọlọ́run (7) Èṣù dà bíi kìnnìún tó ń ké ramúramù (8) Ọ̀rọ̀ ìparí (12-14) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ 1 Pétérù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) 1 Pétérù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá 1 Pétérù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt 1 Pétérù ojú ìwé 1615