Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìwé Kíróníkà Kejì

Orí

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Sólómọ́nì béèrè ọgbọ́n (1-12)

    • Ọrọ̀ Sólómọ́nì (13-17)

  • 2

    • Ìmúrasílẹ̀ fún kíkọ́ tẹ́ńpìlì (1-18)

  • 3

    • Sólómọ́nì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ tẹ́ńpìlì (1-7)

    • Ibi Mímọ́ Jù Lọ (8-14)

    • Àwọn òpó bàbà méjì (15-17)

  • 4

    • Pẹpẹ, Òkun àti àwọn bàsíà (1-6)

    • Ọ̀pá fìtílà, tábìlì àti àgbàlá (7-11a)

    • Bí wọ́n ṣe parí àwọn ohun tó wà nínú tẹ́ńpìlì (11b-22)

  • 5

    • Ìmúrasílẹ̀ ayẹyẹ ṣíṣí tẹ́ńpìlì (1-14)

      • Wọ́n gbé Àpótí wọnú tẹ́ńpìlì (2-10)

  • 6

    • Sólómọ́nì bá àwọn èèyàn náà sọ̀rọ̀ (1-11)

    • Àdúrà tí Sólómọ́nì fi ṣí tẹ́ńpìlì (12-42)

  • 7

    • Ògo Jèhófà kún inú tẹ́ńpìlì (1-3)

    • Ayẹyẹ ìṣílé (4-10)

    • Jèhófà fara han Sólómọ́nì (11-22)

  • 8

    • Àwọn iṣẹ́ ìkọ́lé míì tí Sólómọ́nì ṣe (1-11)

    • Ó ṣètò bí wọ́n á ṣe máa jọ́sìn ní tẹ́ńpìlì (12-16)

    • Àwọn ọkọ̀ òkun Sólómọ́nì (17, 18)

  • 9

    • Ọbabìnrin Ṣébà wá sọ́dọ̀ Sólómọ́nì (1-12)

    • Ọrọ̀ Sólómọ́nì (13-28)

    • Ikú Sólómọ́nì (29-31)

  • 10

    • Ísírẹ́lì ṣọ̀tẹ̀ sí Rèhóbóámù (1-19)

  • 11

    • Ìjọba Rèhóbóámù (1-12)

    • Àwọn ọmọ Léfì tí wọ́n jẹ́ adúróṣinṣin lọ sí Júdà (13-17)

    • Ìdílé Rèhóbóámù (18-23)

  • 12

    • Ṣíṣákì gbógun ti Jerúsálẹ́mù (1-12)

    • Òpin ìjọba Rèhóbóámù (13-16)

  • 13

    • Ábíjà di ọba Júdà (1-22)

      • Ábíjà ṣẹ́gun Jèróbóámù (3-20)

  • 14

    • Ikú Ábíjà (1)

    • Ásà di ọba Júdà (2-8)

    • Ásà ṣẹ́gun 1,000,000 àwọn ará Etiópíà (9-15)

  • 15

    • Àwọn àtúnṣe tí Ásà ṣe (1-19)

  • 16

    • Àdéhùn tí Ásà bá Síríà ṣe (1-6)

    • Hánáánì bá Ásà wí (7-10)

    • Ikú Ásà (11-14)

  • 17

    • Jèhóṣáfátì di ọba Júdà (1-6)

    • Wọ́n ń kọ́ àwọn èèyàn káàkiri (7-9)

    • Ẹgbẹ́ ológun Jèhóṣáfátì (10-19)

  • 18

    • Jèhóṣáfátì dara pọ̀ mọ́ Áhábù (1-11)

    • Mikáyà sọ tẹ́lẹ̀ pé wọn ò ní ṣẹ́gun (12-27)

    • Wọ́n pa Áhábù ní Ramoti-gílíádì (28-34)

  • 19

    • Jéhù bá Jèhóṣáfátì wí (1-3)

    • Àwọn àtúnṣe tí Jèhóṣáfátì ṣe (4-11)

  • 20

    • Àwọn orílẹ̀-èdè tó yí Júdà ká gbógun tì í (1-4)

    • Jèhóṣáfátì gbàdúrà pé kí Ọlọ́run ran òun lọ́wọ́ (5-13)

    • Ìdáhùn tí Jèhófà fún un (14-19)

    • Ọlọ́run gba Júdà là lọ́nà ìyanu (20-30)

    • Òpin ìjọba Jèhóṣáfátì (31-37)

  • 21

    • Jèhórámù di ọba Júdà (1-11)

    • Èlíjà kọ̀wé ránṣẹ́ (12-15)

    • Ìgbẹ̀yìn Jèhórámù kò dáa (16-20)

  • 22

    • Ahasáyà di ọba Júdà (1-9)

    • Ataláyà fipá gbàjọba (10-12)

  • 23

    • Jèhóádà dá sí ọ̀rọ̀ náà; wọ́n fi Jèhóáṣì jọba (1-11)

    • Wọ́n pa Ataláyà (12-15)

    • Àwọn àtúnṣe tí Jèhóádà ṣe (16-21)

  • 24

    • Ìjọba Jèhóáṣì (1-3)

    • Jèhóáṣì tún tẹ́ńpìlì ṣe (4-14)

    • Jèhóáṣì di apẹ̀yìndà (15-22)

    • Wọ́n pa Jèhóáṣì (23-27)

  • 25

    • Amasááyà di ọba Júdà (1-4)

    • Ogun ja Édómù (5-13)

    • Amasááyà bọ òrìṣà (14-16)

    • Ogun ja Jèhóáṣì ọba Ísírẹ́lì (17-24)

    • Ikú Amasááyà (25-28)

  • 26

    • Ùsáyà di ọba Júdà (1-5)

    • Ohun tí ẹgbẹ́ ológun Ùsáyà gbé ṣe (6-15)

    • Ùsáyà agbéraga di adẹ́tẹ̀ (16-21)

    • Ikú Ùsáyà (22, 23)

  • 27

    • Jótámù di ọba Júdà (1-9)

  • 28

    • Áhásì di ọba Júdà (1-4)

    • Síríà àti Ísírẹ́lì ṣẹ́gun rẹ̀ (5-8)

    • Ódédì kìlọ̀ fún Ísírẹ́lì (9-15)

    • Ọlọ́run rẹ Júdà wálẹ̀ (16-19)

    • Áhásì bọ̀rìṣà; ikú rẹ̀ (20-27)

  • 29

    • Hẹsikáyà di ọba Júdà (1, 2)

    • Àwọn àtúnṣe tí Hẹsikáyà ṣe (3-11)

    • Ó fọ tẹ́ńpìlì mọ́ (12-19)

    • Ó mú iṣẹ́ ìsìn tẹ́ńpìlì pa dà sí bó ṣe wà tẹ́lẹ̀ (20-36)

  • 30

    • Hẹsikáyà ṣe Ìrékọjá (1-27)

  • 31

    • Hẹsikáyà mú ìbọ̀rìṣà kúrò (1)

    • Àwọn èèyàn ti àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì lẹ́yìn bó ṣe yẹ (2-21)

  • 32

    • Senakérúbù gbógun ti Jerúsálẹ́mù (1-8)

    • Senakérúbù pẹ̀gàn Jèhófà (9-19)

    • Áńgẹ́lì pa àwọn ọmọ ogun Ásíríà (20-23)

    • Àìsàn tó ṣe Hẹsikáyà àti ìgbéraga rẹ̀ (24-26)

    • Àwọn àṣeyọrí Hẹsikáyà àti ikú rẹ̀ (27-33)

  • 33

    • Mánásè di ọba Júdà (1-9)

    • Mánásè ronú pìwà dà ìwà búburú rẹ̀ (10-17)

    • Ikú Mánásè (18-20)

    • Ámọ́nì di ọba Júdà (21-25)

  • 34

    • Jòsáyà di ọba Júdà (1, 2)

    • Àwọn àtúnṣe tí Jòsáyà ṣe (3-13)

    • Wọ́n rí Ìwé Òfin (14-21)

    • Àsọtẹ́lẹ̀ Húlídà nípa àjálù (22-28)

    • Jòsáyà ka ìwé náà fún àwọn èèyàn (29-33)

  • 35

    • Jòsáyà ṣètò Ìrékọjá ńlá kan (1-19)

    • Fáráò Nékò pa Jòsáyà (20-27)

  • 36

    • Jèhóáhásì di ọba Júdà (1-3)

    • Jèhóákímù di ọba Júdà (4-8)

    • Jèhóákínì di ọba Júdà (9, 10)

    • Sedekáyà di ọba Júdà (11-14)

    • Ìparun Jerúsálẹ́mù (15-21)

    • Àṣẹ tí Kírúsì pa pé kí wọ́n tún tẹ́ńpìlì kọ́ (22, 23)