YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 Lẹ́tà sí Àwọn Ará Fílípì Orí 1 2 3 4 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ìkíni (1, 2) Ọpẹ́ ni fún Ọlọ́run; Àdúrà Pọ́ọ̀lù (3-11) Ìhìn rere ń tẹ̀ síwájú kódà lójú wàhálà (12-20) Ààyè mi jẹ́ ti Kristi, ikú mi jẹ́ èrè (21-26) Ẹ máa hùwà lọ́nà tó yẹ ìhìn rere (27-30) 2 Ìrẹ̀lẹ̀ Kristẹni (1-4) Ìrẹ̀lẹ̀ Kristi àti ìgbéga rẹ̀ (5-11) Ẹ máa ṣiṣẹ́ ìgbàlà yín yọrí (12-18) Ẹ máa tàn bí ìmọ́lẹ̀ (15) Ó rán Tímótì àti Ẹpafíródítù (19-30) 3 Ẹ má ṣe gbẹ́kẹ̀ lé ẹran ara (1-11) Ohun gbogbo jẹ́ àdánù nítorí Kristi (7-9) Mò ń nàgà láti gba èrè náà (12-21) Ìlú ìbílẹ̀ wa wà ní ọ̀run (20) 4 Ìṣọ̀kan, ayọ̀, èrò tí ó tọ́ (1-9) Ẹ má ṣe máa ṣàníyàn nípa ohunkóhun (6, 7) Pọ́ọ̀lù mọyì ẹ̀bùn àwọn ará Fílípì (10-20) Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (21-23) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Fílípì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Fílípì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Fílípì—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Fílípì ojú ìwé 1565