YAN Ọ̀KAN Ìwé Bíbélì Jẹ́nẹ́sísì Ẹ́kísódù Léfítíkù Nọ́ńbà Diutarónómì Jóṣúà Àwọn Onídàájọ́ Rúùtù 1 Sámúẹ́lì 2 Sámúẹ́lì 1 Àwọn Ọba 2 Àwọn Ọba 1 Kíróníkà 2 Kíróníkà Ẹ́sírà Nehemáyà Ẹ́sítà Jóòbù Sáàmù Òwe Oníwàásù Orin Sólómọ́nì Àìsáyà Jeremáyà Ìdárò Ìsíkíẹ́lì Dáníẹ́lì Hósíà Jóẹ́lì Émọ́sì Ọbadáyà Jónà Míkà Náhúmù Hábákúkù Sefanáyà Hágáì Sekaráyà Málákì Mátíù Máàkù Lúùkù Jòhánù Ìṣe Róòmù 1 Kọ́ríńtì 2 Kọ́ríńtì Gálátíà Éfésù Fílípì Kólósè 1 Tẹsalóníkà 2 Tẹsalóníkà 1 Tímótì 2 Tímótì Títù Fílémónì Hébérù Jémíìsì 1 Pétérù 2 Pétérù 1 Jòhánù 2 Jòhánù 3 Jòhánù Júùdù Ìfihàn Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 Lẹ́tà sí Àwọn Ará Róòmù Orí 1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí 1 Ìkíni (1-7) Ó wu Pọ́ọ̀lù láti lọ sí Róòmù (8-15) Ìgbàgbọ́ yóò mú kí olódodo wà láàyè (16, 17) Àwọn èèyàn tí kò ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run kò ní àwíjàre (18-32) À ń rí àwọn ànímọ́ Ọlọ́run nínú àwọn ohun tó dá (20) 2 Ìdájọ́ Ọlọ́run lórí àwọn Júù àti Gíríìkì (1-16) Bí ẹ̀rí ọkàn ṣe ń ṣiṣẹ́ (14, 15) Àwọn Júù àti Òfin (17-24) Ìkọlà ọkàn (25-29) 3 “Kí Ọlọ́run jẹ́ olóòótọ́” (1-8) Àwọn Júù àti àwọn Gíríìkì wà lábẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ (9-20) Òdodo nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ (21-31) Gbogbo èèyàn kò kúnjú ìwọ̀n ògo Ọlọ́run (23) 4 A pe Ábúráhámù ní olódodo nítorí ìgbàgbọ́ (1-12) Ábúráhámù ni baba àwọn tó ní ìgbàgbọ́ (11) Ìlérí tí a gbà nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ (13-25) 5 Èèyàn pa dà bá Ọlọ́run rẹ́ nípasẹ̀ Kristi (1-11) Ikú wá nípasẹ̀ Ádámù, ìyè wá nípasẹ̀ Kristi (12-21) Ẹ̀ṣẹ̀ àti ikú tàn dé ọ̀dọ̀ gbogbo èèyàn (12) Ìwà òdodo kan (18) 6 Ìgbé ayé ọ̀tun nípasẹ̀ batisí sínú Kristi (1-11) Ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹ̀ṣẹ̀ jọba nínú ara yín (12-14) Láti ẹrú ẹ̀ṣẹ̀ sí ẹrú Ọlọ́run (15-23) Èrè ẹ̀ṣẹ̀ ni ikú; Ẹ̀bùn Ọlọ́run ni ìyè (23) 7 Àpèjúwe bí a ṣe dá wa sílẹ̀ lọ́wọ́ Òfin (1-6) Òfin fi ẹ̀ṣẹ̀ hàn (7-12) Ó ń bá ẹ̀ṣẹ̀ wọ̀yá ìjà (13-25) 8 Ìyè àti òmìnira nípasẹ̀ ẹ̀mí (1-11) Ẹ̀mí ìsọdọmọ ń jẹ́rìí (12-17) Ìṣẹ̀dá ń dúró de òmìnira àwọn ọmọ Ọlọ́run (18-25) ‘Ẹ̀mí ń bá wa bẹ̀bẹ̀’ (26, 27) Ọlọ́run yàn wá ṣáájú (28-30) Ìfẹ́ Ọlọ́run mú kí a di aṣẹ́gun (31-39) 9 Pọ́ọ̀lù kẹ́dùn nítorí Ísírẹ́lì tara (1-5) Ọmọ Ábúráhámù tòótọ́ (6-13) Ohun tí Ọlọ́run bá yàn, kò sẹ́ni tó lè yí i pa dà (14-26) Ohun èlò ìrunú àti ti àánú (22, 23) Àṣẹ́kù nìkan la ó gbà là (27-29) Ísírẹ́lì kọsẹ̀ (30-33) 10 Bí ọwọ́ èèyàn ṣe lè tẹ òdodo Ọlọ́run (1-15) Ìkéde ní gbangba (10) Kíképe Jèhófà ń yọrí sí ìgbàlà (13) Ẹsẹ̀ àwọn oníwàásù rẹwà (15) Wọ́n kọ ìhìn rere (16-21) 11 Ọlọ́run ò kọ Ísírẹ́lì sílẹ̀ pátápátá (1-16) Àpèjúwe igi ólífì (17-32) Ọgbọ́n Ọlọ́run mà jinlẹ̀ o (33-36) 12 Ẹ fi ara yín fún Ọlọ́run ní ẹbọ ààyè (1, 2) Ẹ̀bùn ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀, àmọ́ ara kan náà (3-8) Ìmọ̀ràn lórí ìgbé ayé Kristẹni tòótọ́ (9-21) 13 Ìtẹríba fún àwọn aláṣẹ (1-7) Sísan owó orí (6, 7) Ìfẹ́ ni àkójá Òfin (8-10) Máa rìn bí ìgbà téèyàn ń rìn ní ọ̀sán (11-14) 14 Má ṣe dá ọmọnìkejì rẹ lẹ́jọ́ (1-12) Má ṣe mú ẹlòmíì kọsẹ̀ (13-18) Mú kí àlàáfíà àti ìṣọ̀kan wà (19-23) 15 Ẹ tẹ́wọ́ gba ara yín bí Kristi ti ṣe (1-13) Pọ́ọ̀lù, ìránṣẹ́ àwọn orílẹ̀-èdè (14-21) Àwọn ibi tí Pọ́ọ̀lù fẹ́ rìnrìn àjò lọ (22-33) 16 Pọ́ọ̀lù sọ̀rọ̀ nípa Fébè tó jẹ́ òjíṣẹ́ (1, 2) Wọ́n ń kí àwọn Kristẹni tó wà ní Róòmù (3-16) Ìkìlọ̀ pé kí wọ́n yẹra fún ìyapa (17-20) Àwọn tó ń bá Pọ́ọ̀lù ṣiṣẹ́ kí àwọn ará (21-24) A ti wá mọ àṣírí mímọ́ (25-27) Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Róòmù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN (TÍ A TÚN ṢE LỌ́DÚN 2018) Róòmù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Yorùbá Róòmù—Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1001061100/univ/wpub/1001061100_univ_sqr_xl.jpg nwt Róòmù ojú ìwé 1500