Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ERÉ ALÁWÒRÁN

Ta Ló Yàn Láti Sin Jèhófà?

Fàlà láti ibi orúkọ àwọn èèyàn inú Bíbélì síbi àlàyé tó bá irú ẹni tí wọ́n jẹ́ mu. Wá èyí tó yàn láti sin Ọlọ́run nínú àwọn èèyàn náà.