Bokọ wo wa te ri ọsan ti o laju fẹnẹfẹnẹ ni ẹkọ Baibol ghaan?
Gin gbẹ oniye ọkan di o kọ ẹ: Gin gbẹ ọnẹ ti o mu broṣọ we gbẹ rẹ di o biri uwọ kọ ẹkọ Baibol, wẹrẹ wo nemi birọ ẹkọ Baibol ni wẹbsait ẹnẹ, jw.org.
ẸWẸLẸ ỌṢỌGUA
Rọ ẹkori ọkan-ọkan, gbaa lu ubirọ ti a ṣe deghere (A) owun biri ẹsẹn Baibol ghaan (B) ti o ta arun ma ẹkoko ubo ni ẹkọ we. Daju gin o nẹ ẹsẹn Baibol bọbọ ti a mu amẹn ni, gin di a “rọ.”
ẸWẸLẸ ẸGBELEMEEJI
Ọfọ ọṣọgua (C) ni abẹ Kọ Gba Man Ni wewe urun ti a wa kọ. Origho tie ghaan (D) wewe ẹkoko ubo ni ẹkọ we. Rọ ẹsẹn Baibol ghaan, di wo gba iwanran ni ubirọ ghaan. Kẹnrẹn wo ka ṣọn vidio ghaan (E).
Jọlọ ṣọn ifoto ghaan biri ọfọ ti a ya gba wewe ro (F), kuro di wo ro biri wo wa te gba iwanran ni urun ti Irẹye Bọbọ Gin (G).
ẸWẸLẸ TI O TIN OGUN
A lo Nikọ Wo Kọ biri Gba Fẹnẹ Gho (H) gba mu ẹkọ ọkan-ọkan to ogun. Ya deeti ti a gba kọ ẹkọ we tan. Ni abẹ Dan Eyi Gho (I) a wa mu urun mirẹn ti wo nemi ṣe gbẹ rẹ. Ni abẹ Fẹ Alẹ Ro Ni (J) wo wa ri urun mirẹn mirẹn ti wo nemi rọ wẹrẹ gba gho.
Biri wo wa te nemi fẹ ẹsẹn Baibol
Ọrukọ iwe Baibol (A) we owun a wa ṣọgua ya, ti o tin gege wa ṣe origho ro (B), kuro di a re ya ẹsẹn Baibol we (C). Ni ewe, iwe Jọn 17:3 soro gbẹ iwe Jọn, origho 17, ẹsẹn 3.