Re listi urun ti o winọrọn

Re listi urun ti o wi iwe we

ẸKỌ 36

Ṣe Uṣe Ọgbarara ni Urun Dede

Ṣe Uṣe Ọgbarara ni Urun Dede

Irẹye dede re fẹ ukun ti o nẹ uṣe ọgbarara, wẹrẹ ti o ka fọ ọrọnfọ. Jihova ka fẹ di aghan olukun ro ṣe uṣe ọgbarara kẹnrẹn. Dẹ, eyi ee ka ya ṣiṣe ni onuwe teri irẹye gidijẹ ee nẹ uṣe ọgbarara. Ere bokọ re ka winọrọn ni oniye ma ṣe uṣe ọgbarara ni urun dede?

1. Nikọ re ṣe ẹkoko urun ti o lẹghẹ ẹ yẹle di ẹnẹ ṣe uṣe ọgbarara?

Ẹnẹ ma biri irẹye mirẹn ṣe uṣe ọgbarara, ẹnẹ mughan Jihova gin ẹnẹ fẹ ọfọ ro, kẹnrẹn gba mu ọghọ gbẹ ẹ. Ro o tẹnrẹn: Jihova man urun dede ti ẹnẹ ka ro biri ti ẹnẹ ka ṣe. (Ibru 4:13) O ka ri ẹnẹ ni ira-ki-ira ti ẹnẹ ma ṣe uṣe ọgbarara, kẹnrẹn eyi ka lẹghẹ ẹ nẹ ọyọ. Ọfọ ro gin: “Teri gin ỌLUWA [Jihova] ee fẹ ọfọ aghan ọṣika, di o ka gba aghan ọlọgbarara man ara.”Owe 3:32.

2. Ewe bọbọ bokọ wun ẹnẹ kele nemi ṣe uṣe ọgbarara ni udoẹye ẹnẹ kpọjọ?

Jihova fẹ di ẹnẹ “fọ ọrọnfọ gbẹ ara” ẹnẹ. (Sẹkaraya 8:16, 17) Nikọ wun eyi jẹ sin? O ma wu gin ẹnẹ winọrọn biri ẹbi ẹnẹ, aghan ti ẹnẹ ka ba ṣe uṣẹ, aghan omere ẹnẹ ẹkẹnrẹn biri ebirẹn wẹrẹ ọṣuṣẹ udẹrini fọ, ẹnẹ ee ka kpitekun wẹrẹ gba fọ ọfọ ulẹghẹ. Irẹye ti o ka ṣe uṣe ọgbarara ee ka ji urun ọlurun wẹrẹ gba nini aghan jẹ. (Rọ Lẹfitikọs 19:21 biri Ẹfisọs 4:28.) Kẹnrẹn aghan ka san iwẹn origho ti aghan ma jẹ. (Rom 13:5-7) Ni ewe eyiwe biri ewe mirẹn, “ẹnẹ ka fẹ gba ọgbarara gba ṣe urun-ki-urun dede.”—Ibru 13:18.

3. Nikọ re ṣe ere ti o wi uṣe ọgbarara ti a ṣe?

A ma man ẹnẹ ni uṣe ọgbarara, irẹye mirẹn ka gbiyẹle ẹnẹ. Ẹnẹ ka tin irẹye dede ti o wi ujọ ẹyin gba nẹ ẹmi kiko, ṣiṣi biri ẹbi ti o nẹ wuwu ka ṣe. Ẹnẹ ka nẹ ẹmi ti o fẹn. “Di ẹkọ ti a kọ aghan ni ubara Oriṣẹ Ọnugbe ẹnẹ ka mu ara lẹfun” ti ubara uṣe ọgbarara ẹnẹ kẹnrẹn, ti o wa lẹghẹ aghan mirẹn ti ee te wi ujọ we gba fẹ wa sẹn Jihova.—Taitọs 2:10.

KỌ GBA MAN NI

Ṣọn biri Jihova te ro ni ubara uṣe ọgbarara ẹnẹ biri ere ti uṣe ọgbarara ẹnẹ ka mu gbẹ ẹnẹ. Kẹnrẹn kọ biri wo wa te nemi ṣe uṣe ọgbarara ni ukalẹ-ki-ukalẹ ni udoẹye rẹ.

4. Jihova fẹ ọfọ uṣe ọgbarara

Rọ Sam 44:21 biri Malakai 3:16, kuro di aghan fọ ni ubirọ ghaan:

  • Ni ẹmi rẹ, nikọ wo gba ro gin ee yẹle di ẹnẹ ro gin ẹnẹ nemi mu urun yẹrẹ gbẹ Jihova?

  • Bokọ wo ro gin o te ṣe Jihova ni ẹnẹ ma fọ ọrọnfọ, o wu di o roro ṣiṣe?

Aghan ọmẹtie ma fọ ọrọnfọ, ara ka yọn ọsa biri ore ti o bi aghan. Ẹnẹ ma fọ ọrọnfọ, ẹnẹ ka lẹghẹ Jihova nẹ ọyọ

5. Ka ṣe uṣe ọgbarara ni ira dede

Irẹye gidijẹ ro gin aa nemi ṣe uṣe ọgbarara wẹrẹ fọ ọrọnfọ ni ira dede. Dẹ, ro ni ubara urun ti o lẹghẹ ẹ yẹle di ẹnẹ ka ṣe uṣe ọgbarara ni ira dede. Lu VIDIO we.

Rọ Ibru 13:18, kuro di aghan fọ ni ubirọ ghaan. Bokọ ẹnẹ te nemi ṣe uṣe ọgbarara . . .

  • ni ẹbi ẹnẹ?

  • ni ubo uṣẹ wẹrẹ ni uli-ẹkọ?

  • ni ukalẹ mirẹn?

6. Uṣe ọgbarara ka mu ere gbẹ ẹnẹ

Ni ọṣọgua, uṣe ọgbarara nemi ṣiṣi urun ti o wa mu ẹkpikpomẹ bọbọ gbẹ ẹnẹ. Dẹ, ni ugbẹyin, gba fọ ọrọnfọ re ṣe urun ti o san ju ti a ṣe. Rọ Sam 34:12-16, kuro di aghan fọ ni ubirọ we:

  • Bokọ uṣe ọgbarara te nemi lẹghẹ udoẹye rẹ san ni?

  1. Ọkọ biri obirẹn ti o ṣe uṣe ọgbarara ka lẹghẹ udo ọkọ biri obirẹn aghan gba ni ni

  2. Olori ubo uṣẹ ka nemi gbiyẹle ọṣuṣẹ ti o ka ṣe uṣe ọgbarara

  3. Ọma-aja ti o ṣe uṣe ọgbarara ka nẹ ọrọnrọn ọrukọ ni eju aghan ọṣuṣẹ udẹrini

IRẸYE BỌBỌ GIN: “Itekun tie ee ba urun-ki-urun jẹ.”

  • Nikọ wo teri ro kpe ni ọrọnfọ gin itekun dede re ka bi Jihova inọ?

NIKỌ WO KỌ?

Jihova fẹ di aghan olukun ro ka fọ ọrọnfọ ni urun dede ti aghan gin biri gba ṣe.

Gba Fẹnẹ Gho

  • Nikọ re ṣe ewe bọbọ ti ẹnẹ kele nemi ṣe uṣe ọgbarara?

  • Ni ẹmi rẹ, nikọ wo gba ro gin ee yẹle di ẹnẹ ro gin ẹnẹ nemi mu urun yẹrẹ gbẹ Jihova?

  • Nikọ wo teri ro gba ka fẹ fọ ọrọnfọ ni ira dede?

Dan Eyi Gho

FẸ ALẸ RO NI

Bokọ ọsa biri ore te nemi gba uṣe ọgbarara kọ ọtọn aghan?

Ka Fọ Ọrọnfọ (1:44)

Nikọ o gba san di ẹnẹ ka ṣe urun ti ẹnẹ naṣi gin ẹnẹ wa ṣe?

Da Nina Rẹ Ni, Wo Wa Ri Iṣẹ Gidijẹ Gba (9:09)

Ko ni uro tabi o yẹle di ẹnẹ san iwẹn origho, o ma wu di a maa lo o gẹrẹrẹ.

“Iwẹn Origho—Wo Lati Saan?” (The Watchtower, September 1, 2011)

Nikọ re gbe ọnọkẹnrẹn ọkan ti ee nẹ uṣe ọgbarara ṣi gba yi udoẹye ro dẹ, gba ra ṣe uṣẹ ti aa kele nini oniye jẹ?

“Mo Kọ Gin Jihova Ka Ṣe Aninọ Biri Gba Muji” (The Watchtower, May 1, 2015)