February 12-18
SAM 5-7
Ẹrin 118 Biri Iṣẹ | Ọfọ Ọṣọgua ti Ọlaga Wa Fọ (uṣẹju 1)
1. Kpe Tama Jihova O Ma Wu Di Irẹye Mirẹn Biri Uwọ Ṣe Uṣe ti Ee San
(uṣẹju 10)
O nẹ ira ti ọyọ Defid gba tafu wun ẹwọ teri uṣe irẹye mirẹn (Sam 6:6, 7)
O buru Jihova gbẹ utiẹyin (Sam 6:2, 9; w21.03-E 15 ¶7-8)
Teri Defid jọlọ gbiyẹle Jihova, eyi tin wun ẹyin gba tama a (Sam 6:10)
BI ARA RẸ RỌ, ‘Mo winọrọn ṣe di ukpeọrọnfọ mi ni to ti mo wa gba kpe tama Jihova ni ira ti irẹye ma ṣe mi urun ti ee jọ?’—w20.07-E 8-9 ¶3-4.
2. Uwa Ẹmi
(uṣẹju 10)
3. Rirọ Baibol Usoro
(uṣẹju 4) Sam 7:1-11 (th ẹkọ 10)
4. Mimu Arun ni Ọfọ
(uṣẹju 3) KURI ẸGẸRIFO RA WỌ ẸGẸRIFO. (lmd ẹkọ 1 ẹkori 3)
5. Mimu Arun ni Ọfọ
(uṣẹju 2) IRA TI ỌFỌ MA ṢI ỌFỌ. Maa gba arun to ẹsẹn-Baibol-ki-ẹsẹn-Baibol, dẹ fẹ ewe gba jẹ di ọnẹ man gin uwọ, ọkan ni ẹbu aghan Oṣẹri Jihova rẹẹn. (lmd ẹkọ 2 ẹkori 4)
6. Liludẹ Buru
(uṣẹju 2) KURI ẸGẸRIFO RA WỌ ẸGẸRIFO. Ọluli we fẹ biri uwọ jẹ iyan. (lmd ẹkọ 4 ẹkori 5)
7. Wiwewe Urun ti Wo Kpe Ni Ọrọnfọ
(uṣẹju 4) Iṣemughan. Ijwfq-E 64—Origho Ọfọ: Nikọ Re Ṣe ti Aghan Oṣẹri Jihova Ee Gba Nẹ Ẹwọ ni Uge-Ki-Uge ti A Gba Gbe Ẹri ni Arugha? (lmd ẹkọ 3 ẹkori 4)
Ẹrin 99
8. Iyẹn Urun ti A Ṣe ni Uṣẹ Oye We Kpọdọn
(uṣẹju 15) Ọfọ ti a fọ ni ara. A ma rọ ọfọ ti a wowo ti o ti branṣ ọfisi wa ni ubara iyẹn urun ti a ṣe ni uṣẹ oye we kpọdọn kuro, kpe aghan bọbọ ti o wi iṣikalẹ di aghan fọ ni ubara urun ti o san omirẹn ti o wi Uṣẹ ti Aghan Oṣẹri Jihova Ṣe ni Alẹ Ẹye We Dede ni Ọdọn Uṣẹ-Ujọ 2023. Fẹ alẹ ọfọ ni arun aghan ọwowo iyẹn rire bọbọ ti wo fẹsẹn ṣi alẹ, di aghan fọ ni ubara urun ti o nemi mu ẹkọ ṣi, ti o ṣi gbẹ aghan ni uṣẹ oye we ni ọdọn ti o bọghọ we.
9. Ẹkọ Baibol ti Ujọ Dede
(uṣẹju 30) bt origho 5 ¶16-22, ẹkpetin ti o wi peji 42