Re listi urun ti o winọrọn

Re listi urun ti o wi iwe we

February 24–March 2

OWE 2

February 24–March 2

Ẹrin 35 Biri Iṣẹ | Ọfọ Ọṣọgua ti Ọlaga Wa Fọ (uṣẹju 1)

UWA TI O TI ỌFỌ ORIṢẸ WA

1. Nikọ Re Ṣe ti O Gba San Di Wo Ka Da Agbigbẹn Ṣiṣe Ẹkọ Baibol ti Ẹwọ Rẹ Kawọ?

(uṣẹju 10)

O wa mughan gin ọrọnfọ we kọn uwọ eju (Owe 2:​3, 4; w22.08-E 18 ¶16)

O wa mu utiẹyin gbẹ rẹ gba ka da ero ti o jọ (Owe 2:​5-7; w22.10-E 19 ¶3-4)

O wa ṣe di ukpeọrọnfọ rẹ ni ni (Owe 2:​11, 12; w16.09-E 23 ¶2-3)

BI ARA RẸ RỌ, ‘Bokọ mo wa te won ni, ni ewe biri mo te ṣe ẹkọ Baibol ti ẹwọ mi kawọ?’

2. Uwa Ẹmi

(uṣẹju 10)

  • Owe 2:7—Bokọ Jihova te mu “ikirimọn ṣi . . . gbẹ aghan ti ẹwọ ro fẹn”? (it-1-E 1211 ¶4)

  • Uwa ẹmi bokọ wo ri ni Baibol ti a rọ ni ọjijala eyiwe ti wo wa fẹ fọ ni ubara ro?

3. Rirọ Baibol Usoro

(uṣẹju 4) Owe 2:​1-22 (th ẹkọ 12)

KA WOWO ỌFỌ WE NI ODE

4. Mimu Arun ni Ọfọ

(uṣẹju 4) KURI ẸGẸRIFO RA WỌ ẸGẸRIFO. Wewe gbẹ oniye ọkan biri won wa te ri urun ti o nemi mu utiẹyin gbẹ aghan ọkọ biri obirẹn ni jw.org. (lmd ẹkọ 1 ẹkori 3)

5. Liludẹ Buru

(uṣẹju 3) IRA TI ỌFỌ MA ṢI ỌFỌ. Ni ọfọ ti aghan fọ ni ara ṣi, ọnẹ gin gbẹ rẹ origho ọfọ ọkan ti o wu wun. Mu magazin ti o fọ ni ubara origho ọfọ rẹn gbẹ ọnẹ. (lmd ẹkọ 9 ẹkori 3)

6. Ọfọ

(uṣẹju 5) lmd ẹkọ mirẹn mirẹn ọṣọgua ẹkori 8—Origho Ọfọ: O Yẹle Di Ọkọ Biri Obirẹn Ka Ṣe Ara Ọkan. (th ẹkọ 13)

KA DO UDOẸYE OLELE KRAIST

Ẹrin 96

7. Wo Ka Jẹ Ayọn Fifẹ Uwa ti A Mu Yẹrẹ?

(uṣẹju 15) Ọfọ ti a fọ ni ara.

Aghan ọmọṣọn, aghan ka jẹ ayọn fifẹ urun wẹrẹ uwa ti a mu yẹrẹ? Iwanran rẹ ma ṣe in, o nẹ ubo ọkan ti wo kele nemi ri uwa ti o wọrun ju urun-ki-urun mirẹn dede. Ubo we Baibol rẹn. Uwa we ka ṣe oye ọfọ Oriṣẹ! (Owe 2:​4, 5) Wo wa ri uwa eyiwe ni wo ma ka jọlọ ira ṣi gba rọ Baibol kpira kpira, biri ni wo ma ka fẹ alẹ urun ti wo rọ gẹrẹrẹ. Wo ma ka ṣe eyiwe, wo wa ka jọlọ jẹ ayọn rirọ Baibol, kẹnrẹn wo wa ka kọ urun gidijẹ!

  • Nikọ re ṣe ubirọ bọbọ ti wo nemi bi ara rẹ rọ biri wo winọrọn rọ Baibol? (w24.02 32 ¶2-3)

  • Nikọ re nemi mu utiẹyin gbẹ rẹ gba ri iwanran ubirọ ghaan?

Vidio ti o lele ara ti akpuja ro ṣe Kọ gbẹ Ni Ẹwọ Aghan Olukun Jihova nemi mu utiẹyin gbẹ rẹ gba kọ biri a te ro jẹn ni ubara urun ti wo rọ ni Baibol.

Lu VIDIO we Kọ gbẹ Ni Ẹwọ Aghan Olukun Jihova—Ebẹl.

Rọ Jẹnẹsis 4:​2-4 biri Ibru 11:4. Kuro bi aghan ti o wi iṣikalẹ rọ:

  • Bokọ Ebẹl te mughan gin owun olukun Jihova?

  • Bokọ Ebẹl te ṣe di ukpeọrọnfọ ti won nẹ ni Jihova ni ni?

  • Bokọ wo te nemi ṣe di ukpeọrọnfọ rẹ ni ni?

8. Ẹkọ Baibol ti Ujọ Dede

Ọfọ ti A Wa Gba Gba Ẹkọ We To Ogun (uṣẹju 3) | Ẹrin 102 Biri Iṣẹ